Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò

Wọ́n kéde àrùn COVID-19 àkọ́kọ́ ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò lọ́jọ́ lóṣù kẹta ọdún 2020.

Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 ní Congo
ÀrùnCOVID-19
Irú kòkòrò èrànSARS-CoV-2
IbiRepublic of the Congo
Ìjásílẹ̀ àkọ́kọ́Wuhan, China
Index caseBrazzaville
Arrival date14 March 2020
(4 years, 1 month, 2 weeks and 4 days)
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn1,087 (as of 25 June)[1]
Active cases594 (as of 25 June)
Iye àwọn tí ara wọn ti yá456 (as of 25 June)
Iye àwọn aláìsí
37 (as of 25 June)

Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ àtúnṣe

Lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kìíní ọdún 2020 ni àjọ elétò ìlera àgbáyé, World Health Organization (WHO) jẹ́rìí pé ẹ̀rànkòrónà, Covid-19, ni ó ń fa àìsàn èémí láàárín àwọn ènìyàn kan lágbègbè Wuhan,ní Ìpínlẹ̀ Hubei, lórílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jábọ̀ rẹ̀ fún àjọ WHO lọ́jọ́ kokànlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019.[2][3]

Iye ìjàm̀bá ikú àrùn Covid-19 kéré sí ti àrùn SARS, Severe acute respiratory syndrome tó bẹ́ sílẹ̀ lọ́dún 2003,[4][5] ṣùgbọ́n jíjàkálẹ̀ àrùn náà lágbára ju SARS lọ, pàápàá jù lọ iye àwọn ènìyàn tí àrùn náà ń pa lápapọ̀.[6][4]

Ẹ yẹ̀yí wò àtúnṣe

Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 lórílẹ̀-èdè Olómìnira Benin

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "MINISTERE DE LA SANTE, DE LA POPULATION, DE LA PROMOTION DE LA FEMME ET DE L'INTEGRATION DE LA FEMME AU DEVELOPPEMENT". www.sante.gouv.cg. Retrieved 2020-06-25. 
  2. Elsevier. "Novel Coronavirus Information Center". Elsevier Connect. Archived from the original on 30 January 2020. Retrieved 15 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Reynolds, Matt (4 March 2020). "What is coronavirus and how close is it to becoming a pandemic?". Wired UK. ISSN 1357-0978. https://www.wired.co.uk/article/china-coronavirus. 
  4. 4.0 4.1 "Crunching the numbers for coronavirus". Imperial News. Archived from the original on 19 March 2020. Retrieved 15 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "High consequence infectious diseases (HCID); Guidance and information about high consequence infectious diseases and their management in England". GOV.UK (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 3 March 2020. Retrieved 17 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "World Federation Of Societies of Anaesthesiologists – Coronavirus". www.wfsahq.org. Archived from the original on 12 March 2020. Retrieved 15 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)