Àwọn Òpó Márùún Ìmàle

Àwọn Òpó Márùún Islam (Arabic: أركان الإسلام) ni a n pe awon ojuse marun to se dandan fun gbogbo musulumi. Awon ojuse wonyi ni:

  • Shahada (ijẹrisi igbagbo ninu ọkan Olorun ati pe anọbi muhammad ẹrusin ati ojiṣẹ rẹ ni nṣe),
  • Irun (adura ojoojumo fún àwọn ada yanrí wakati máàrún),
  • Itọ ọrẹ anu Zakat jẹ ọrọyàn lẹ kan lọdun fún gbogbo musulumi ti o ba ní owo nipa mọ Ka odindin ọdún tí bukata kan ko kọlù. Ida kàn ogójì ni yi o fi tọ ọrẹ (ọpọlọpọ Musulumi ma n saba yọ zakat wọn losu Ramadan nitori lada to pọ ninu oṣu náà)
  • Awe osu Ramadan jẹ awẹ ọrọ yan nigba osu Ramadan fún gbogbo musulumi, ati
  • Haji (irinajo lo si Mekka, ibi ti Masjid al-Haram (Mosalasi Mimo) wa, to je mosalasi to gbajumo julo ninu Imale).


Itokasi àtúnṣe