Isodipupo (ti a ma n tọka si nipasẹ aami agbelebu ×, ati nipasẹ aami aarin-laini ⋅, ati lori kọnputa nipasẹ aami akiyesi *) jẹ ọkan ninu awọn iṣẹ iṣiro alakọbẹrẹ mẹrin. Awọn isiro alakobere toku jẹ afikun, iyokuro, ati pipin.

3 × 4 = 12, a le to ami méjìlá sí orí ìlà gbọlọjọ mẹ́ta tí ikọ̀ọ̀kan ní àmìn mẹ́rin tàbí sí orí ìlà nínàró mẹ́rin tí ikọ̀ọ̀kan wọn ní àmìn mẹ́ta.
Àmì ìsọdipúpọ̀.

A le ri isodipupo gegebi atunse afikun.




Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

 
 
 
 
Ìròpọ̀ Ìyọkúrò Ìsọdipúpọ̀ Division
+ × ÷