Tejuosho Market jẹ́ ọjà gbajúgbajà kan ní Ojuelegba-ọjú ọnà Itire Yaba, Ìpínlẹ̀ Èkó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ọjà náà pín sí ọ̀nà méjì (Phase I and Phase II), ó sì ní ọ̀pọ̀lọpò ohun àmúyẹ bí i iná, omi, ilé-oúnjẹ, ilé-ìfowópamọ́, àyè láti gbọ́kọ̀ sí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[2]

Àwòrán ọjà Tejuosho

Ní ọdún díẹ̀ sẹ́yìn, ijàm̀bá iná ba ọjà náà jẹ́, tí ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó, Stormberg Engineering Limited, àti First Bank of Nigeria pawọ́ pọ̀ láti tún ọjà náà ṣe.[3]

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Tejuosho Shopping Complex commissioned". Miriam Ekene-Okoro. The Nation. 16 August 2014. Retrieved 9 July 2015. 
  2. "Tejuosho market raises bar in shopping". Temitayp Ayetoto. The Nation. 19 August 2014. Retrieved 9 July 2015. 
  3. "Fashola commissions Tejuosho market". Vanguard Nigeria. 16 August 2014. Retrieved 9 July 2015.