Adeola Fayehun

Oníwé-Ìròyín

Adeola Eunice Oladele Fayehun (bíi ni ọjọ́ kẹfà oṣù keje ọdún 1984) jẹ́ ọmọ Nàìjíríà, ó sì jẹ oniroyin tí ó má ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ sí àwọn ọmọ ẹ̀yà Áfríkà.[1][2] [3]

Adeola Fayehun
Ọjọ́ìbíAdeola Oladele Fayehun
Oṣù Keje 6, 1984 (1984-07-06) (ọmọ ọdún 39)
Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànEunice Fayehun
Ẹ̀kọ́Olivet College (B.A., 2007)
Iṣẹ́Journalist
Ìgbà iṣẹ́2011-present
Gbajúmọ̀ fúnKeeping It Real with Adeola!
Websiteadeolafayehun.com

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ àtúnṣe

Wọ́n bí Adeola sì Nàìjíríà, òun sì ni àbíkẹ́yìn nínú àwọn ọmọ márùn-ún tí àwọn òbí rẹ bí.[4] Àwọn òbí rẹ ni Rev. Dr. Solomon Ajayi Oladele ati Margaret Ibiladun Oladele. Ní ọdún 2013, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Olivet College ni Michigan ni orile-ede United States of America, nibe sì ni ó ti gboyè nínú ìmọ̀ Mass communications àti Journalism ni ọdún 2007.[5][6] Ní ọdún 2008, ó gboyè masters degree láti ilé ẹ̀kọ́ CUNY Graduate School of Journalism.[7]

Iṣẹ́ àtúnṣe

Adeola bẹ́ẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí a gbèrò yín jáde ni CUNY TV.[7] Ní oṣù kokanla ọdún 2011, bẹ́ẹ̀rẹ̀ ètò ìròyìn Keeping it real with Adeola!.[8][9]Ó tún sì ṣé fún ilé iṣẹ́ The Nation tí ó má ń ṣe ìwé ìròyìn ni Nàìjíríà.[10] Óun ló dá African Spotlight kalẹ̀.[11] Ní ọdún 2015, ohùn àti Omoyele Sowore jọ ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nurọ̀ fún olórí orílẹ̀-èdè Zimbabwe, Robert Mugabe, wọn si béèrè pé ìgbà wo ni ó fé fí ipò olórí orílè-èdè sílẹ̀.[12][13][14] Ní ọdún 2013, ó ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nurọ̀ fún olórí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, Goodluck Jonathan ni ojú títí New York, ó sì béèrè pé kí ni Jonathan ṣe nípa ọ̀rọ̀ àwọn Boko Haram tí ó da ìlú rú.[15] Adeola si ṣé pelu Sahara Reporters, ó sì má ń ba wọn kọ nípa oselu ilé Áfríkà. Ó ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nurọ̀ fún olórí àti igbá kejì olórí orílè-èdè Nàìjíríà ni ọdún 2015.[16][17] Ní ọdún 2011, ó fẹ́ Victor Fayehun ni Nàìjíríà.[18] Òun àti ọkọ rẹ̀ jọ dá KIRWA foundation kalẹ̀ láti lè pèsè fún àwọn tí ó ní àìsàn ni Áfríkà.[19]

Ẹ̀bùn àtúnṣe

Year Award Category Result
2008 Foreign Press Association, New York, NY Outstanding Academic And Professional Achievement Gbàá [4]
2014 Ethiopian Satellite News Network (ESAT), Washington DC Excellence In Journalism For Democracy AwardGbàá [20]
2015 CUNY Graduate School of Journalism Best One Woman Show Gbàá [1]


Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 Snow, Jackie (9 March 2016). "Meet Adeola, Nigeria's Jon Stewart: An interview with Adeola Fayehun, the host of Nigeria's Keeping It Real with Adeola". Lenny Letter. http://www.lennyletter.com/culture/a295/meet-adeola-nigerias-jon-stewart/. Retrieved 9 March 2016. 
  2. Ssali, Shaka (13 May 2015). "Straight Talk Africa: Adeola Fayehun, Host of Sahara TV's "Keeping It Real with Adeola"". Voice of America News. http://www.voanews.com/media/video/2766409.html. Retrieved 14 March 2016. 
  3. "Just in: Adeola of Sahara Reporters quits Sahara TV". Vanguard News. November 1, 2017. Retrieved May 30, 2022. 
  4. 4.0 4.1 "Scholarship Winners 2008". Foreign Press Association. Archived from the original on 10 March 2016. Retrieved 9 March 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Olivet College to celebrate Founders' Day Feb. 18". Olivet College. 2 February 2015. Archived from the original on 15 March 2016. Retrieved 14 March 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "Career Spotlight: Adeola Fayehun, Journalist". Naija Enterprise. 25 November 2015. Retrieved 14 March 2016. 
  7. 7.0 7.1 Olumhense, Eseosa (24 August 2013). "Meet the Nigerian Face Behind one of Africa's Most Popular News Satires". Premium Times. http://www.premiumtimesng.com/arts-entertainment/143341-meet-the-nigerian-face-behind-one-of-africas-most-popular-news-satires.html. Retrieved 9 March 2016. 
  8. Oshodi, Darasimi (27 January 2014). "Adeola Fayehun, the 'bad girl' of Nigerian TV". Inspirational Bursts: Darasimi Oshodi. Retrieved 14 March 2016. 
  9. Ssali, Shaka (5 March 2014). "Straight Talk Africa: Adeola Fayehun, Host of Sahara TV's "Keeping It Real with Adeola"". Voice of America News. https://www.youtube.com/watch?v=Vy8u7YCeR-k. Retrieved 14 March 2016. "Interview starts at 5:14" 
  10. "Meet the woman who embarrassed Mugabe in Nigeria". Nehanda Radio. 2015-06-02. Retrieved 2017-08-01. 
  11. "About". African Spotlight. Archived from the original on 9 March 2016. Retrieved 9 March 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  12. Fayehun, Adeola (31 May 2015). "SaharaReporters Crew Encounter With Pres. Robert Mugabe In Nigeria". SaharaTV. Retrieved 9 March 2016. 
  13. Thamm, Marianne (5 June 2015). "Nigeria's favourite satirist goes global after ambushing Robert Mugabe". Daily Maverick - Guardian Africa network (The Guardian). https://www.theguardian.com/world/2015/jun/05/nigeria-satirist-adeola-fayehun-robert-mugabe-ambush. Retrieved 9 March 2016. 
  14. Freeman, Colin (3 June 2015). "How a Nigerian television reporter brought Robert Mugabe to account: TV journalist Adeola Fayehun ambushes Zimbabwean leader and asks why him he hasn't stepped down". The Daily Telegraph. https://www.telegraph.co.uk/news/worldnews/africaandindianocean/zimbabwe/11647333/How-a-Nigerian-television-reporter-brought-Robert-Mugabe-to-account.html. Retrieved 9 March 2016. 
  15. Fayehun, Adeola (24 September 2013). "SaharaTV Interview with Goodluck Jonathan On The Streets Of New York". SaharaTV. Retrieved 9 March 2016. 
  16. Fayehun, Adeola (29 September 2015). "Adeola Fayehun Interviews President Buhari". SaharaTV. Retrieved 14 March 2016. 
  17. Fayehun, Adeola (1 June 2015). "SaharaTV Exclusive Interview With Vice President Yemi Osinbajo". SaharaTV. Retrieved 14 March 2016. 
  18. Adams, Suzanne (February 2011). "Chronicle". FPA News (Foreign Press Association) 237 (93): 4. Archived from the original on 10 March 2016. https://web.archive.org/web/20160310131754/http://www.foreignpressassociation.org/fpa/wp-content/uploads/2011/10/NL_2011_931.pdf. Retrieved 9 March 2016. 
  19. "About". KIRWA Foundation. Archived from the original on 10 March 2016. Retrieved 9 March 2016. 
  20. Fikir, Dudi (21 May 2014). "Ethiopia: Adeola speech at ESAT 4th year anniversary". Ethiopian Satellite Television, ESAT. Retrieved 9 March 2016.