Afara fourth Mainland jẹ afara to gun to 38 km ti ìjoba ìpínlè Eko, Nàìjíríà se, o so Lagos Island papò mo Itamaga, ni Ikorodu . [1] Afara naa jẹ ọna opopona 2×4, o si ni ònà fún BRT. Ìreti wà pé ouni yo je Afara keji ti o gunjulo ni Afrika. Yó ní plazas toll meta, yó sì gbà Lagos lagoon kojá. [2] ìjọba Sẹnetọ Bola Ahmed Tinubu, Gómìnà tẹ́lẹ̀ rí ní ìpínlẹ̀ Èkó ló mú àbá afara náà wá. A gbero lati bẹrẹ kíkó rè ni ọdun 2017, ọdun aadota lẹhin ti a da ipinlẹ naa ati ọdun merindinlogbon lẹhin tí a kó afara third mainland, nireti pe yoo pari ni ọdun 2019,[3] . Wón ni kíkó rè ma gbà iye owo 844 bilionu ni isuna 2017.[4][5]. Ni oṣu kẹsan ọdun 2020, Ijọba ipinlẹ Eko dabtí o jé owo miiran ti $2.2 million fun kíkó rè. Awọn ile 800 ni a nireti lati wó. [6][7][8]

Mapu Afara third ati fourth ní ìpinlè Eko
Àwòrán bi afara mainland se gba erukusu atowoda kan.


Ijade Afara náà

Ni Oṣu Kẹrin ọdun 2021, awọn ilé-isé mefa ni o so pé àwon nifesi kíkó afara naa, isé tí owo kíkó rè lé ní 2.5 billion USD. Ni Oṣu Kejila, wón ni eni ti wón bá mú yo di mímò.[9]

Ni January 2022, Gomina Ipinle Eko, Babajide Sanwo-Olu, fi to gbogbo eniyan leti pe awọn ile-iṣẹ mẹta ti de ipele ikẹhin, ati pe wọn yoo gba adehun ni Oṣu Kẹta 2022.

Awon Ìtókasí àtúnṣe

  1. "Lagos assembly ll support delivery of fourth mainland bridge". https://m.guardian.ng/news/lagos-assembly-ll-support-delivery-of-fourth-mainland-bridge. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. Nwannekanma, Bertram (September 29, 2020). "800 houses for demolition as Lagos budgets $2.2b of 4th Mainland Bridge". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved September 12, 2022. 
  3. "LASG to begin construction of 4th Mainland Bridge this year – Commissioner". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-03. 
  4. "Construction of Fourth Mainland Bridge to start this year". TheGuardian. NAN. Retrieved 4 November 2017. 
  5. "Lagos: N844billion 4th Mainland Bridge project up in 2019". TheSun. Punch. Retrieved 4 November 2017. 
  6. "You are being redirected...". businessday.ng. Retrieved 2021-01-03. 
  7. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0
  8. "795 houses to go for Lagos Fourth Mainland Bridge | The Nation". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-04. Retrieved 2021-01-03. 
  9. "Lagos says Fourth Mainland Bridge contract with funding ready in December 2021 - Nairametrics" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-04-28. Retrieved 2022-01-15.