Audrey Olatokunbo Ajose (ọjọ́-ìbí c. 1937) jẹ́ Àgbẹjọ́rò àti Akòwé ọmọ Nàìjíríà. Ó ṣiṣẹ́ bí aṣojú orílẹ̀-èdè rẹ̀ sí Scandinavia láti ọdún 1987 sí 1991. [1]

Omoba
Audrey Olatokunbo Ajose
Ọjọ́ìbí1937
Iṣẹ́
  • Lawyer
  • writer
Parent(s)
  • Omoba Oladele Ajose
  • Beatrice Spencer Roberts

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé Rẹ̀ Àti Ẹ̀kọ́ àtúnṣe

Ọmọbìnrin Ọmọba Oladele Ajose àti Beatrice Spencer Roberts.[2] Audrey Ajose jẹ́ ọmọ obìnrin ilẹ̀ òkèèrè kan tí ó fẹ́ ọmọ Nàìjíríà. [3] Ó kọ ẹ̀kọ́ ìròyìn ní Regent Polytechnic. Ọ́ kọ ẹ̀kọ́ àti àdaṣe òfin ṣùgbọ́n tún tẹ̀síwájú láti ṣiṣẹ́ ní ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́. [4] Ó tún kọ ẹ̀kọ́ nípa'theology' [5] [6]ó sì kọ́ ẹ̀kọ́ nípa 'theology' ní ilé ìjọsìn Lutheran.

Àwọn Iṣẹ́ Tí A Yàn àtúnṣe

  • Yomi's Adventures, juvenile fiction (1964)[7]
  • Yomi in Paris, juvenile fiction (1966)

[1]

Àwọn Ìtọ́ka Sí àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 "Ajose, Audrey (Nigeria)". Literary Map of Africa. Ohio State University. 
  2. "Tribute to Late Oladele Adebayo Ajose". The Sun (Nigeria). July 17, 2003. http://news.biafranigeriaworld.com/archive/2003/jul/17/0074.html. 
  3. "Foreign women married Nigerians, nigerwives, foreign women in nigeria". nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-27. 
  4. "Audrey Ajose | Academic Influence". academicinfluence.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-27. 
  5. "AUDREY AJOSE: How I dared soldiers who held us captive in newsroom during 1985 coup - The Nation Newspaper" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-12-11. Retrieved 2022-05-27. 
  6. "MFR Audrey Olatokunbo Ajose". Government College Ibadan Old Boy's Association. Archived from the original on 2023-04-26. Retrieved 2023-04-26. 
  7. "National Academic Digital Library of Ethiopia". ndl.ethernet.edu.et. Retrieved 2022-05-27.