Abiola Ahmed Akinbiyi tí orúkọ orí ìtàgé rẹ̀ ń jẹ́ Bella Shmurda[1] jẹ́ ólórin àtí éní tí mán kó órín ní ìlú Nàìjíríà.[2][3] Ó di gbajúmọ̀ nígbà tí orin rẹ̀ "Vision 2020" jáde, pẹ̀lú àtúnkọ tí ó kọ pẹ̀lú olórin Nàìjíríà tí ó ń jẹ́ Olamide.[4]

Bella Shmurda
Background information
Orúkọ àbísọAkinbiyi Abiola Ahmed
Irú orinAfrobeats, world
Occupation(s)Singer
LabelsDagbana Rebulik
Associated acts

Àwọn ìtọ́ka sí àtúnṣe

  1. "BELLA SHMURDA- THE BUILDUP TO HIGH TENSION". Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 11 July 2021. Retrieved 17 November 2021. 
  2. "I was enrolled into Tailoring - Bella Shmurda". Vanguard (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 28 July 2021. Retrieved 7 October 2021. 
  3. "Bella Shmurda serves new sophomore EP, 'High tension2.0'". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 July 2021. Retrieved 25 September 2021. 
  4. "Bella Shmurda ft. Olamide – Vision 2020 (Remix)". LEGIT9JA - Music and More (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 14 September 2019. Retrieved 26 March 2021.