Benito Juárez (Pípè: [beˈnito ˈxwaɾes]; (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹta ọdún 1806 tí ó sì kú ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1872)[1][2] Benito Pablo Juárez García, jẹ́ agbẹjọ́rò àti olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Mexico tí àwọn ènìyàn Zapotec láti Oaxaca tó di Ààrẹ ilẹ̀ Mexico ní ẹ̀marùn-ún: 1858–1861 fún ìgbà díè, 1861–1865, 1865–1867, 1867–1871 ati 1871–1872.[3]

Benito Jose Pablo Juárez García
Ààrẹ ilẹ̀ Mẹ́ksíkò
In office
January 15, 1858 – April 10, 1864
AsíwájúIgnacio Comonfort
Arọ́pòMaximilian I of Mexico
In office
May 15, 1867 – July 18, 1872
AsíwájúMaximilian I of Mexico
Arọ́pòSebastián Lerdo de Tejada
Alákóso Àgbà ilẹ̀ Mẹ́ksíkò
In office
April 10, 1864 – May 15, 1867
MonarchMaximilian I
AsíwájúArarẹ̀
bíi Ààrẹ ilẹ̀ Mẹ́ksíkò
Arọ́pòArarẹ̀
bíi Ààrẹ ilẹ̀ Mẹ́ksíkò
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1806-03-21)21 Oṣù Kẹta 1806
San Pablo Guelatao, Oaxaca
Aláìsí18 July 1872(1872-07-18) (ọmọ ọdún 66)
Mexico City, Federal District
Ẹgbẹ́ olóṣèlúLiberal
(Àwọn) olólùfẹ́Margarita Maza

Itokasi àtúnṣe

  1. "Benito Juarez". Encyclopedia of World Biography. Retrieved February 18, 2011. 
  2. "Benito Juárez (March 21, 1806 - July 18, 1872)". Banco de Mexico. Retrieved February 18, 2011. 
  3. "Juárez' Birthday". Sistema Internet de la Presidencia. Retrieved 2009-03-23.