Chioma Ajunwa (Tsioma Ajunwa; ojoibi December 25, 1970 in Ahiara Mbaise Ipinle Imo), je elere ori papa lati Nigeria, to ti figba kan gba boolu elese fun egbe agbaboolu awon obinrin Nigeria.[1] Ohun ni omo Nigeria akoko to gba eso wura Olympiki ati bakanna obinrin ara Afrika akoko to gba eso wura Olympiki ninu idije ori papa. O gba ipo kinni She ninu ifojinna awon obinrin ni Olympiki 1996 ni Atlanta, pelu ifo 7.12m ni igbiyanju akoko re ni idopin idije.[2] Bakanna o tun je oga ibise ni Nigeria Police Force ni igbana.

Chioma Ajunwa
Medal record
Women's Athletics
Adíje fún Nàìjíríà Nàìjíríà
Olympic Games
Wúrà 1996 Atlanta Ìfòjìnnà
World Indoor Championships
Fàdákà 1997 Paris Ìfòjìnnà

O gba eso wura ni Awon Ere Gbogbo Afrika 1991. O je fifofindelona kuro ni ere-idaraya fun odun merin leyin to kuna idanwo doping ni 1992.


Itokasi àtúnṣe

  1. Chioma Ajunwa - FIFA competition record
  2. "Chioma Ajunwa Biography and Statistics". Sports Reference. Retrieved 2009-10-14. 

External links àtúnṣe