Eileen Heckart

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Eileen Heckart ni a bini óṣu kẹta, ọdún 1919 to sÌ kú ní óṣù kejìlá, ọdún 2001 ti jẹ óṣèrè lóbinrin to siṣẹ fun ọgọta ọdun[1].

Eileen Heckart
Eileen Heckart
Ọjọ́ìbíAnna Eileen Herbert
(1919-03-29)Oṣù Kẹta 29, 1919
Columbus, Ohio, U.S.
AláìsíDecember 31, 2001(2001-12-31) (ọmọ ọdún 82)
Norwalk, Connecticut, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaOhio State University (B.A.)
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1943–2000
Olólùfẹ́
John Harrison Yankee, Jr.
(m. 1942; died 1997)
Àwọn ọmọ3

Igbèsi Àyè Àràbinrin naa àtúnṣe

Heckart ni a bi si ọdọ Anna Eileen Herbert ni ilú Columbus, Ohio. Orukọ iya óṣèrè lóbinrin naa njẹ Esther ti baba rẹ si njẹ Leo Herbert[2][3]

Ni ọdun 1942, Heckart fẹ̀ John Harrison Yankee to jẹ̀ ólólufẹ rẹ lati collegi. Awọn mejèèji bi ọmọ ọkunrin mẹta ti ikan ninu awọn ọmọ óṣèrè lóbinrin naa Luke Yankee kọ nipa itan igbèsi Ayè iya rẹ[4][5][6].

Heckart jẹ Democrat tosi pade arẹ Lyndon B. Johnson ni ilè funfun ni ọdun 1967[7]. Óṣèrè lobinrin naa jẹ ọmọ ijọ Roman catholic[8].

Ni óṣú December, ọdun 2001, óṣèrè lóbinrin naa kú si ilè rẹ ni Norwalk, Connecticut ni ọmọ ọdun meji lèèlọgọrin lóri aisan jẹjẹrẹ titi lung. Wọn sin óṣèrè lóbinrin naa si ita Music Box Theatre ni Manhattan, New York[9][10][11][12].

Ẹkọ àtúnṣe

Eileen jade lati ilè iwe giga ti ipinlẹ Ohio nibi ti o ti ka ere oritage[13]. Oṣèrè lóbinrin naa tẹsiwaju lati kọ ere óri itage ni Studio ti HB ni New York City[14].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla àtúnṣe

Eileen gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo. Ósèrè lóbinrin naa gba Ami Ẹyẹ ti Tony, Emmy, Drama Desk, Drama league ati Golden Globe[15][16][17]

Itokasi àtúnṣe