Fàájì FM jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ kan tí ó jẹ́ ẹ̀ka ilé-iṣẹ́ Daar Communications tí ó jẹ́ ti ọ̀gbẹ́ni Raymond Dokpesi jẹ́ olùdásílẹ̀ rẹ̀. Ilé-iṣẹ́ Fàájì wà ní ìlú AlágbàdoÌpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Fàájì FM bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ọjọ́ Kíní oṣù Kejìlá, ọdún 2012, tí olùdarí àgbà fún ẹ̀ka ti rédíò, ìyẹn ọ̀gbẹ́ni Kenny Ogungbe jẹ́ ẹni tí ó kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ẹ́fẹ́ níbẹ̀.[1][2] [3]

Faaji FM
CityÌpínlẹ̀ Èkó
Broadcast areaNàìjíríà
FrequencyFM: 106.5MHz
OwnerDAAR Communications Plc
Sister stationsRaypower 100.5 FM

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Faaji FM marks 3rd anniversary". TheNetng. Retrieved July 10, 2017. 
  2. "Faaji Fm radio presenter attacked Over ‘affair’ with housewife". KemiFilani.com. Retrieved July 10, 2017. 
  3. "Faaji 106.5 FM launches new Mobile APP". amm.com.ng. Retrieved July 10, 2017. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]