Titilayo Fatima Azeez (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlelógún, osú kejìlá, ọdún 1992) jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù badminton ti orílè-èdè Naijiria.[1] Ní ọdún 2010, ó parí Summer Youth Olympics ní Singapore.[2] Ní ọdún 2011, ó jẹ èbùn ti All-Africa Games ní Maputo, Mozambique.[3]

Àwọn àṣeyọrí rẹ̀ àtúnṣe

All-Africa Games àtúnṣe

Ìdíje àwọn obìnrin méjì

Year Venue Partner Opponent Score Result
2011 Escola Josina Machel,

Maputo, Mozambique

 Grace Daniel   Camille Allisen

  Cynthia Course

22–24, 15–21   Bronze

Ìdíje ti ilẹ̀ Africa àtúnṣe

Obìnrin ọ̀wọ́ kan nìkan

Year Venue Opponent Score Result
2012 Arat Kilo Hall, Addis Ababa, Ethiopia   Grace Gabriel Ofodile 19–21, 21–14, 16–21   Silver

Obìnrin ọ̀wọ́ méjì

Year Venue Partner Opponent Score Result
2014 Lobatse Stadium,

Gaborone, Botswana

  Tosin Damilola Atolagbe   Kate Foo Kune

  Yeldy Louison

16–21, 23–21, 17–21   Bronze

Ìdíje àgbáyé ti BWF àtúnṣe

Obìnrin ọ̀wọ́ kan nìkan

Year Tournament Opponent Score Result
2013 Nigeria International   Tosin Damilola Atolagbe 21–16, 15–21, 22–20 Winner

Women's doubles

Year Tournament Partner Opponent Score Result
2014 Nigeria International   Tosin Atolagbe  
Shamim Bangi
  Hadia Hosny
5–11, 10–11, 10–11 Runner-up
2014 Lagos International   Tosin Atolagbe   Dorcas Adesokan

  Maria Braimoh

19–21, 20–22 Runner-up
2014 Uganda International   Tosin Atolagbe   Dorcas Adesokan

  Augustina Sunday

14–21, 21–9, 21–12 Winner
2013 Nigeria International   Tosin Atolagbe   Augustina Sunday

  Deborah Ukeh

18–21, 13–21 Runner-up

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe