Hlonipha Mokoena jẹ òpìtàn ilẹ̀ South Africa, ní Wits Institute for Social and Economic Research ti University of the Witwatersrand. Ó jẹ́ alámọ̀já nínú ìtàn àkọọ́lẹ̀ ti South Africa.[1] Ó fìgbà kan ṣiṣẹ́ ní ẹ̀ka ìmọ̀-ẹ̀dá ènìyàn ní Columbia University.[2] Ó gba oyè PhD ní University of Cape Town ní ọdún 2005. [3] Ìwé rẹ̀, ìyẹn, Magema Fuze: The Making of a Kholwa Intellectual, dá lórí Magema Magwaza Fuze, tó jẹ́ agbọ̀rọ̀sọ ti Zulu àkọ́kọ́ tó máa ṣe àtẹ̀jáde ìwé nínú èdẹ̀ náà.[4][5]

Àtòjọ àwọn ìwé tó ti tẹ̀jáde àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Hlonipha Mokoena". Socialdifference.columbia.edu. Retrieved 14 August 2018. 
  2. "Hlonipha Mokoena - Wits Institute for Social and Economic Research". Wiser.wits.ac.za. Archived from the original on 29 July 2018. Retrieved 14 August 2018. 
  3. "Hlonipha Mokoena". The Conversation. Retrieved 14 August 2018. 
  4. "Hlonipha Mokoena « Black Portraiture[s] Conferences". Blackportraitures.info. Archived from the original on 30 July 2018. Retrieved 14 August 2018. 
  5. Tallie, T.J.; Couper, Scott (1 January 2012). "Hlonipha Mokoena. Magema Fuze: The Making of a Kholwa Intellectual. Moss Mashamaite, The Second Coming: The Life and Times of Pixley ka Isaka Seme, The Founder of the ANC". Journal of Natal and Zulu History 30 (1): 101–106. doi:10.1080/02590123.2012.11964180.