[1]

Iganga
Iganga is located in Uganda
Iganga
Iganga
Location in Uganda
Coordinates: 00°36′54″N 33°29′06″E / 0.61500°N 33.48500°E / 0.61500; 33.48500
Country Uganda
RegionEastern Region of Uganda
Sub-regionBusoga sub-region
DistrictIganga District
Elevation
3,670 ft (1,120 m)
Population
 (2014 Census)
 • Total53,870[2]
Websiteigangamc.go.ug

Iganga jẹ́ Ìlú kan tí ó wà ní apá Ìlà Oòrùn orílẹ̀ èdè Uganda. Ibẹ̀ ni ó jẹ́ ilé agbára, àṣ àṣẹ ìjọba Uganda, Ìlú yí náà ni ó tún jẹ́ pẹpẹ ọrọ̀ ajé jùlọ fún àwọn ènìyàn ilẹ̀ Uganda.

Ibi tí Ìlú yí wà àtúnṣe

Iganga wà ni erékùṣù ilẹ̀ Uganda, tí ó ní ilẹ̀ tí ó tó ìwọ̀n márùndín láàádọ́ta (45 Kilometres) ìyẹn (25 mi) tí a bá rí ojú ọ̀nà tí ó ja sí ìlú ńlá Jinja àti Tororo. Tí a bá ṣí gbogbo rẹ̀ pọ̀, yóò ma tó bí ìwọ̀n kìlómítà ọgọ́rùún ólé Mọ́kàndínlógún (118 kilometres (73 mi), bá kàn náà ló ja sí Mbale Tìbú tòró Iganga jẹ́ :0°36'54.0"N, 33°29'06.0"E (Ìbú rẹ̀ :0.6150; Òró rẹ̀ :33.4850).

Ìbojúwò Ìlú náà àtúnṣe

Àwọn ohun tí ókóra jọ sí Iganga tí ó fi gbayì tobẹ́ẹ̀ ni : Ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ internet cafes, ilé ìrura lóríṣiríṣi àti Ọjà elérò rẹpẹtẹ tí kò kíkà sí Ibùdókọ̀ èrò. Lára àwọn iṣẹ́ àkànṣe tó lààmì laaka láàrín ìlú náà ni : iṣṣẹ́ àkànṣe DevelopNet Iganga Project, tí ó kó Internet cafe àti community center sínú fún àwọn àjọ tí kìí ṣe tìjọba àti àjọ Ìbílẹ̀ lábẹ́lé (NGO/CBO Forum). Iṣẹ́ àkànṣe International Hand Iganga ni ó jẹ́ ti ìjọba t is atí ó wà ní agbègbè náà láti ṣe ìkúnpá fún iṣẹ́ àkànṣe nípa èt ti ètò ẹ̀kọ́ àti ìdàgbàsókè àwọn àjọ tí kìí ṣe ti ìjọba.

Ètò ìrìnà àtúnṣe

Ibùdókọ̀ Ọkọ̀ ojú irin ti Uganda Railways, ni ó bẹ̀rẹ̀ láti ìloro Uganda tí ó la Iganga kọjá sí orílẹ̀-èdè Kenya èyí tí ó jẹ́ márosẹ̀ ni ó lọ sí Malaba, tí ó sì gba Tororo àti Iganga, kọjá lè sí ọ̀nà Jinja àti ìlú Kampala, tí ó jẹ́ ìlú tí ó tóbi jùlọ tí ó sì tún jẹ́ Olú Ìlú fún orílẹ̀-èdè Uganda.

Ònkà Àwọ olùgbé ibẹ̀ àtúnṣe

Ètò ìkànìyàn tí ó wáyé ní́ ọ̣dún 2002, fi hàn wípé ó tó ẹgbẹ̀rún mókàndínlógójì ó lé 500 (39,500) ènìyàn ni ó ń gbé ibẹ̀ lásìkò náà.. Àmọ́ ní ọdún 2010, àjọ tí ó rí sí ònkà ní orílẹ̀-èdè Uganda ìyẹn 'Bureau of Statistics' (UBOS) ṣe ìṣirò iye ènìyàn sí ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta ó lé àádọ́jọ (51,8000), ìṣirò UBOS ní ọdún 2011 jẹ́ (53,700). Nígbà tí ti ọdún 2014 já sí (53,870).

Iganga General Hospital ni ó jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú ohun tí ó wà ní Ignaga, tí ó sì tún jẹ́ ohun ìwúrí fún àwọn ènìyàn agbèbè ibẹ̀. Ilé ìwòsàn ni wọ́n tọ́ka rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó peregedé jùlọ nínú àwọn ilé ìwòsàn ìjọba tị́ ó wà ní Uganda. kódà bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ilé ìwòsàn náà ń bèrè fún ìtọ́jú tó péye, ní títụ́nṣe àti fífi ohun èlò ìgbàlódé síbẹ̀. Ìjọba orílẹ̀-èdè Uganda tún ilé ìwòsàn náà kó ní oṣù kọkànlá ọdún 2015.

Ìgbìyànjú oríṣiríṣi ni wọ́n ti gbé láti dá ètò iṣẹ́ ìwòsàn pàjáwìrì kalẹ̀ ní Iganga. Àwọn àjọ kọ̀ọ̀kan náà tí kìí ṣe ti ìjọba náà ti gbé ̀̀àwọn ìgbésẹ̀ láti ṣètò pàtàkì jùlọ pẹ̀lú ìdàgbàsókè ti ètò 'First responder' pèlú àjọṣepọ̀ Ile-iwe Washington ni St. Louis, LFR International àti Uganda Red Cross Society . [3] ní ọdún 2016

Àwọn àyè tó fani mọ́ra níbẹ̀ àtúnṣe

Àwọn àyè tó fani mọ́ra tó wà ni àárín tàbí nítòsí Iganga ni:

  • Iganga District Administration headquarters
  • Iganga Town Council offices
  • Busoga University, located 1 mile (1.6 km) west of Iganga between Iganga and Jinja
  • Iganga General Hospital, a 120-bed public hospital funded by the Uganda Ministry of Health
  • Iganga Railway Station
  • Iganga central market

Ẹ tún le wo àtúnṣe

  • Orun oorun
  • Atokọ ti awọn ilu ati ilu ni Uganda

Awọn itọkasi àtúnṣe

  1. "Subcounties in Iganga District, Uganda". HURIFO Land Conflict Mapping Tool - Public Maps - HURIFO (in Tagalog). Retrieved 2019-11-19. 
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Later
  3. Lay First Responder Training in Eastern Uganda: Leveraging Transportation Infrastructure to Build an Effective Prehospital Emergency Care Training Program. 

Àwọn ìjásóde àtúnṣe