Jean-Michel Basquiat

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Jean-Michel Basquiat (December 22, 1960 – August 12, 1988) je onisona ara Amerika.[1] O bere bi onisona grafiti ni New York City ni opin ewadun 1970, o si se ni ewadun 1980 aworan kikun Alafarahan-tuntun. Basquiat ku nitori ilokulo heroini ni August 12, 1988, nigba to je omo odun 27.[2]

Jean-Michel Basquiat
Basquiat (1984)
Bíbí (1960-12-22)Oṣù Kejìlá 22, 1960
August 12, 1988(1988-08-12) (ọmọ ọdún 27)
Manhattan, New York City, U.S.
Ilẹ̀abínibí American
Pápá Painting
Movement Postmodern
Influenced by Jean Dubuffet, Pablo Picasso, Robert Rauschenberg, Cy Twombly, Andy Warhol


Itokasi àtúnṣe

  1. Graham Thompson, American Culture in the 1980s, Edinburgh University Press, 2007, p67. ISBN 0-7486-1910-0
  2. Encyclopedia of the African diaspora: origins, experiences, and ..., Volume 1 By Carole Boyce Davies. ABC-CLIO. p. 150.