Alhaji Kareem Adépọ̀jù tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí "Bàbá Wándé" jẹ́ òṣèré, oǹkọ̀tàn àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìràwọ̀ rẹ̀ tàn lágbo àwọn òṣèré tíátà nígbà tí ó kópa olóyè Ọ̀tún nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń "Tí Olúwa Nílẹ̀".[1][2][3]

Kareem Adepoju
Orúkọ mírànBàbá Wándé
Ọmọ orílẹ̀-èdèNaijiria
Iṣẹ́òṣèré . oǹkọ̀tàn
Notable workTi Oluwa Ni Ile

Àwon fiimu tí ó ti kópa àtúnṣe

  • Ti Oluwa Ni Ile
  • Ayọ Ni Mọ Fẹ
  • Abeni
  • Arugba
  • Igbekun
  • Òbúko Dúdú

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe