Keke Márúwá tàbí kẹkẹ Napep je katakata ẹlẹsẹ mẹta ti afi nṣe kabúkabú ni orile-ede Nàìjíríà. [1] Wọn bẹrẹ lílò kẹkẹ yi ní ìgbà ti ọ̀gágun Mohammed Buba Marwa jẹ Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó ní abẹ́ ìṣàkóso ológun.

O kéré ni ìwọnba, osi gba ènìyàn mẹta lẹyìn pẹlú awakọ kan soso ni iwájú.

Etun wo àtúnṣe

Awon itokasi àtúnṣe

  1. "The story of tricycle (Keke) in Nigeria". Tribune Online. 2021-04-10. Retrieved 2022-02-01.