Lizzy jay tí orúkọ àbísọ rẹ̀ gan-an ń jẹ́ Adéyẹlà Adégbolá tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ tún mọ orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ mìíràn sí Ọmọ Ìbàdàn jẹ́ apanilẹ́ẹ̀rín ará Nàìjíríà, agbanilálejò, olórin àti ẹni àwòkọ́ṣe.[1] Abí Lizzy Jay ní ọjọ́ 18 Oṣù Kẹ̀sán, 1995 ní Ìlé Ifẹ̀,Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun. Bàbá rẹ̀ jẹ́ olóṣèlú, tí màmá rè sí jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba.Ó lọ iilé ìwé alákọ̀bẹ̀rẹ̀ àti gírámà ni ìpínlè ọ̀ṣun. Ó lọ sí School of science, Ile-Ife, Osun State.[2]Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Polytechnic Ibadan, ìpínlè Ọ̀yọ́, níbi tí ó ti ka Microbiology.[3]

Iṣẹ́ àtúnṣe

Lẹ́yìn tí Lizzy Jay parí ilé ẹ̀kọ́ gíga, ìṣe ìpanilẹ́ẹ̀rín àti ìṣe tíátà ni ó rawọ́lé.Ni oṣú kẹjọ 2019,ó kéde pé owun ní fíìmù tí owun òbá tí pèsè, àmọ́ Àjàkálẹ àrùn tó kárí-ayé kò jẹ́.[4]

Àpapọ̀ Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. https://allnigeriainfo.ng/biography-of-lizzy-jay-aka-adeyela-adebola/amp/
  2. https://thenationonlineng.net/disappointment-made-popular-lizzy-jay-aka-omo-ibadan/
  3. https://www.nairaland.com/5421105/comedian-lizzyjay-omo-ibadan-celebrates
  4. https://thenationonlineng.net/omo-ibadan-excited-about-first-film-as-producer/

Mir koks (ọ̀rọ̀) 15:41, 9 Oṣù Kẹ̀wá 2020 (UTC)