Ma Ying-jeou (Àdàkọ:Zh; Ọjọ ibi, Oṣu Keje 13, Ọdun 1950) ni Aare ikejila lowolowo orile-ede Olominira ile Saina (ROC), to gbajumo bi Taiwan, o tun je Alaga egbe oloselu Kuomintang, ti a mo gge bi Egbe Oloselu Asorile-ede ti Saina. Teletele o je Alakoso Oro Idajo lati 1993 de 1996, Baale ilu Taipei lati 1998 de 2006, ati Alaga Kuomintang (KMT) lati 2005 de 2007. Ma je didiboyan gege bi Baale ilu Taipei ni 1998 ati leekansi ni 2002. O je didiboyan bi Alaga Kuomintang ni Oṣu Keje Ọjọ 16, Ọdun 2005. O kosesile ni Kínní 13, Ọdun 2007, leyin ti o je fifesunkan latowo Ibise Afesunkan Giga Taiwan pelu esun ikowoje nigba ijoba re gege bi baale ilu Taipei;[1] won mu esun yi kuro nigbeyin. Ma bori ninu idiboyan aare odun 2008. O gori aga gege bi Aare ni Oṣu Karun ọjọ 20, Ọdun 2008, ati gege bi Alaga Kuomintang ni Oṣu Kẹwa 17, ọdun 2009.[2]

Ma Ying-jeou
馬英九
12th-term President of the Republic of China
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
May 20, 2008
PremierLiu Chao-shiuan
Wu Den-yih
Vice PresidentVincent Siew
AsíwájúChen Shui-bian
6th Chairman of the Kuomintang
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
October 17, 2009
AsíwájúWu Po-hsiung
4th Chairman of the Kuomintang
In office
July 27, 2005 – February 13, 2007
AsíwájúLien Chan
Arọ́pòWu Po-hsiung
Mayor of Taipei
In office
December 25, 1998 – December 25, 2006
AsíwájúChen Shui-bian
Arọ́pòHau Lung-pin
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Keje 1950 (1950-07-13) (ọmọ ọdún 73)
Yau Ma Tei, Kowloon, Hong Kong
Ọmọorílẹ̀-èdèRepublic of China
Ẹgbẹ́ olóṣèlúKuomintang
(Àwọn) olólùfẹ́Christine Chow Ma
Alma materNational Taiwan University
New York University
Harvard University
Websitewww.president.gov.tw
Ma Ying-jeou
Traditional Chinese
Simplified Chinese

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe