Matti Taneli Vanhanen (Fi-Matti_Vanhanen.ogg pronunciation ) (ojoibi November 4, 1955) ni Alakoso Agba ile Finland lati 2003 titi di 2010, ati alaga egbe oloselu Keskusta(Centre Party of Finland) tele. Ni apa keji odun 2006 o je Aare Igbimopo Europe. Teletele o je oniroyin.

Matti Vanhanen
Prime Minister of Finland
In office
24 June 2003 – 22 June 2010
ÀàrẹTarja Halonen
DeputyAntti Kalliomäki
Eero Heinäluoma
Jyrki Katainen
AsíwájúAnneli Jäätteenmäki
Arọ́pòMari Kiviniemi
Minister of Defence
In office
17 April 2003 – 24 June 2003
Alákóso ÀgbàAnneli Jäätteenmäki
AsíwájúJan-Erik Enestam
Arọ́pòSeppo Kääriäinen
Member of the Finnish Parliament
for Uusimaa
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
22 March 1991
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kọkànlá 1955 (1955-11-04) (ọmọ ọdún 68)
Jyväskylä, Finland
Ẹgbẹ́ olóṣèlúCentre Party
Alma materUniversity of Helsinki
ProfessionPolitical science
Social science
Journalist
Signature

Ise àtúnṣe

Vanhanen je bibi ni Jyväskylä, omo ojogbon Tatu Vanhanen, to je ekeji-olukowe IQ and the Wealth of Nations, ati Anni Tiihonen.

O ko eko sayensi oloselu ni Yunifasiti ilu Helsinki, o si pari pelu iwe-eri Master ninu Sayensi Awujo ni 1989 [1].

Itokasi àtúnṣe