Microlophus albemarlensis

Alángba àpáta Galápagos (Microlophus albemarlensis), tí wọ́n tún mọ̀ sí  Alángba àpáta Albemarle, jẹ́ ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos  níbi tí ó ti wà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ erékùṣù ìwọ̀ oòrùn archipelago: àwọn erékùṣù ńlá, Isabela, Santa Cruz, Fernandina, Santiago àti Santa Fe, àti àwọn ọ̀pọ̀lọpọ erékùṣù kékèké: Seymour, Baltra, Plaza Sur, Daphne Major àti Rábida.[1] Ó jẹ́ erékùṣù tí ó tàn káàkiri jùlọ nínú gbogbo èyà Galápagos ti Microlophus, a máa ń rí àwọn tókù lẹ́ẹ̀kànkan ní àwọn erékùṣù.[2] Àwọn olùkọ̀wé míràn rò wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí wọ́n maa ń rí ní  Santiago, Santa Cruz, àti Santa Fe (tí ó wà pẹ̀pú àwọn erékùṣù kékèké) yàtọ sí àwọn ẹ̀yà (M. jacobi, M. indefatigabilis àti M. barringtonensis).[3] Wọ́n máa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí mọ́ ìdílé Microlophus  ṣùgbọ́n ní ìgbà láéláè, wọ́n kó wọn pọ̀ pẹ̀lú Tropidurus.

Microlophus albemarlensis
Abo ní erékùṣù Santa Fe
Akọ ní erékùṣù Isabela
Ipò ìdasí
Not evaluated (IUCN 3.1)
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Suborder:
Ìdílé:
Ìbátan:
Irú:
M. albemarlensis
Ìfúnlórúkọ méjì
Microlophus albemarlensis
(Baur, 1890)
Pupa ẹ̀ ní àwọn eŕkùṣù Galápagos
Synonyms[1]
  • Tropidurus albemarlensis Baur, 1890
  • Tropidurus indefatigabilis Baur, 1890
  • Tropidurus jacobii Baur, 1892
  • Tropidurus barringtonensis Baur, 1892
  • Tropidurus grayii barringtonensis Heller, 1903
  • Tropidurus grayii magnus Heller, 1903

Àpèjúwe àtúnṣe

 
Akọ láti erékùṣú Santiago tí ó ń ṣàfihàn ọ̀nà ọ̀fun rẹ̀ dúdú  tó rí pátapàta

Àgba Galápagos lava lizards ma ń gùn tó bíi 50 to 100 mm SVL (ẹnu -dé-ìdí; láì sí ìdí ẹ̀ níbẹ̀ tàbí gùn ju bẹ́ẹ̀ sí SVL) , ìtóbi sí wọn sì yàtọ káàkiri erékùṣù. Àwọn akọ ma ń tóbi ju abo lọ, tí wọ́n sì ma ń wúwo tóbi tó méjì ọ̀kọ̀ọ̀kan abo, ó sì ma ń tobí tó ìwọn 77 sí 91 mm SVL, àkàwé  63–71 mm ti obìnrin.[4]

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 Microlophus albemarlensis, The Reptile Database
  2. Andy Swash; Rob Still; Ian Lewington (2005). Birds, Mammals, and Reptiles of the Galápagos Islands: An Identification Guide. Yale University Press. pp. 120–121. ISBN 978-0-300-11532-1. http://books.google.com/books?id=9s3p8TfXAq8C&pg=PA120. 
  3. Benavides,E; Baum, R.; Snell, H. M.; Snell, H. L.; and Sites, Jr., J.W. (2009).
  4. Stebbins, Robert C.; Lowenstein, Jerold M.; Cohen, Nathan W. (1967). "A Field Study of the Lava Lizard (Tropidurus albemarlensis) in the Galapagos Islands". Ecology 48 (5): 839–851.. doi:10.2307/1933742. JSTOR 1933742.