Mike Ezuruonye tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù Kẹsàn án ọdún 1982, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjị́ríà.

Mike Ezuruonye
Ọjọ́ìbí21 Oṣù Kẹ̀sán 1981

(1981

-09-21) (ọmọ ọdún 42)
Ipinle Eko, Ipinle Anambra, Naijiria
Iṣẹ́Actor

Ìbẹ̀rẹ̀ Ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ àtúnṣe

Wọ́n bí Mike ní ìlú Uzoakoli ní Ìpínlẹ̀ Abia wọ́n bi ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù Kẹsàn án ọdún 1982. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Federal Government College, ní ìlú Wukari, ní Ìpínlẹ̀ Taraba àti ilé-ẹ̀kọ́ Archbishop Aggey Memorial ní Ìpínlẹ̀ Èkó ṣáájú kí ó tó wọ ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Nnamdi Azikiwe láti kọ́ nípa ìmọ̀ ìṣirò owó.[1][2] Ó ṣiṣẹ́ fúngbà díè nílé ìfowó-pamọ́ ṣáájú kí ó tó dara pọ̀ mọ́ eré orí-ìtàgé.[3] Ó ti kópa nínú àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọ̀kan, wọ́n sì ti yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ ti "Òṣèrékùnrin tí ó peregedé jùlọ" látàrí ipa tí ó kó nínú eré Assassin nínú ayẹyẹ ti Africa Movie Academy Awards ọdún 2009.[4][5][6]Bákan náà ni wọ́n tún ti yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ ti "Òṣèrékùnrin tí ó peregedé jùlọ" níbi ayẹyẹ ti Africa Magic Viewers Choice Awards.[7]

Ìgbé ayé rẹ̀ àtúnṣe

Mike ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú aya rẹ̀ Nkechi Nnorom, wọ́n sì ti bímọ ọkùnrin tí wọ́n sọ ní Reynold Nkembuchim Ezuruonye.[8] He has a younger sister, Chichi, who is a Physician in the United Kingdom.[9][10]

Àwọn Àṣàyàn eré rẹ̀ àtúnṣe

  • Endless Passion (2005)
  • Broken Marriage
  • Beyond Reason
  • Critical Decision
  • Unforeseen (2005)
  • Occultic Kingdom
  • Desire (2008)
  • Ropes of Fate (2010)
  • Keep Me Alive (2008)
  • Unforgivable (2014)[11]
  • Calabash Part 1 & Part 2 (2014)
  • The Duplex (2015)[12]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Mike Ezuruonye". Ibakatv. Archived from the original on 24 February 2015. Retrieved 26 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Actor Mike Ezuruonye". Take me to Naija. Retrieved February 28, 2015. 
  3. Kemi Ashefon. "A FAN WANTED ME TO SIGN ON HER BRA — MIKE EZURUONYE". Nigeriafilms. Archived from the original on 3 April 2015. Retrieved 28 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "AMAA 2008: List of Nominees & Winners at ScreenAfrica.com". Archived from the original on 8 February 2010. Retrieved 17 January 2010. 
  5. Orido, George (4 March 2011). "Mike Ezuruonye: The face of African movie". The Standard (Nairobi, Kenya). http://www.standardmedia.co.ke/InsidePage.php?id=2000030475&cid=482&story=Mike%20Ezuruonye:%20The%20face%20of%20African%20movie. Retrieved 9 March 2011. 
  6. "AMAA Nominees and Winners 2009". African Movie Academy Award. Archived from the original on 5 April 2011. Retrieved 9 March 2011.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. Adekunle Adedosu. "Mike Ezuronye, O.C Ukeje, others contest 2015 AMVCA award". Nigerian Entertainment Today. http://thenet.ng/2014/12/mike-ezuronye-o-c-ukeje-others-contest-2015-amvca-award/. 
  8. "Meet Actor Mike Ezuruonye and his Son (PHOTOS) | Akpraise.com". akpraise.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2017-09-03. Retrieved 2018-01-02. 
  9. "Actor Mike Ezuruonye Walks His younger Sister Down the Aisle (See Photos) – Hype Nigeria". hypenigeria.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-01-02. 
  10. "Mike Ezuruonye's Sister Becomes General Practitioner In UK" (in en-gb). Nigeriafilms.com. https://www.nigeriafilms.com/movie-news/92-nollywood-diaspora/29745-mike-ezuruonye-s-sister-becomes-general-practitioner-in-uk. 
  11. Victor Enengedi (August 14, 2013). "Mike Ezuoronye makes Yoruba movie debut". http://thenet.ng/2013/08/mike-ezuruonye-makes-yoruba-movie-debut/. Retrieved February 28, 2015. 
  12. "The Duplex: Mike Ezuruonye, Omoni Oboli scamper in House of Horror". The Tribune. Archived from the original on 4 March 2015. https://web.archive.org/web/20150304074916/http://www.tribune.com.ng/entertainment/item/30659-the-duplex-mike-ezuruonye-omoni-oboli-scamper-in-house-of-horror. Retrieved February 2, 2015. 

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde àtúnṣe


Àdàkọ:Authority control Àdàkọ:Nigeria-actor-stub