Nadine Gordimer (born 20 November 1923) je olukowe ara orílẹ̀-èdè Guusu Afrika to gba Ebun Nobel ninu Litireso ni odun 1991.

Nadine Gordimer
Gordimer (left) with David Grossman
Iṣẹ́Playwright, Novelist
ÈdèEnglish
Ọmọ orílẹ̀-èdèSouth African
Notable worksThe Conservationist, July's People
Notable awardsNobel Prize in Literature
1991


Itokasi àtúnṣe