National Museum of Namibia

National Museum of Namibia jẹ́ musíọ́mù kan fún egungun àwọn ẹranko ní Windhoek, olú ìpínlẹ̀ Namibia. Ó wà lábẹ́ ìdarí ẹ̀ka ìjọba Namibia fún èkọ́ àti àsà.

Ibi tí wọ́n wà àtúnṣe

 
Alte Feste ní Robert Mugabe Avenue, ọdún 2006

National Museum wà ní ibi mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní central Windhoek. Owela Display Centre (lẹyìn ibi ayò Owela) jẹ́ ilé fún àwọn egungun ẹranko àti àwọn ǹkan nípa Sáyẹ́ǹsì ní musíọ́mù náà. Ó wà ní òpópónà Lüderitz, ó sì wà nínú ilé kan náà pẹ̀lú ilé ìkàwé Windhoek Public Library.[1] Ilé náà tí wó lulẹ̀, wọ́n sì ti pa musíọ́mù Owela dé.[2]

Musíọ́mù Alte Feste jẹ́ ilé fún àwọn ohun ìtàn. Ó wà ní Alte Feste (English: Old Fortress) lẹ́gbẹ̀ẹ́ Robert Mugabe Avenue àti Independence Memorial Museum.

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Hillebrecht, Werner (2012). "The National Archives of Namibia". Namibia Library and Archives Service Information Bulletin (Government of Namibia) (1): 4–6. ISSN 2026-707X. Archived from the original on 2023-04-08. https://web.archive.org/web/20230408175835/http://www.nln.gov.na:8081/custom/web/content/2012%20newsletter.pdf. Retrieved 2023-05-07. 
  2. "Owela Museum reduced to rundown homeless shelter". The Namibian: p. 6. 15 March 2023. Archived from the original on 16 March 2023. https://web.archive.org/web/20230316193758/https://www.namibian.com.na/120759/read/Owela-Museum-reduced-to-rundown-homeless-shelter.