Neon Adejo Yunisa, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Neon Adejo ( tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrin lélógún oṣù kẹwàá) jẹ́ akọrin ihinrere ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, olórin àti aṣáájú ìsìn tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí orin “Eze Ebube”. [1]

Igbesiaye àtúnṣe

A bí Neon Adejo ni ọjọ́ kẹrin lélógún Oṣù Kẹwàá ní ìkòyí, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà . Òun ni àkọ́bí nínú àwọn ọmọ mẹ́fà nínú ìdílé àwọn òbi rẹ̀. [2] Ó dàgbà sínú ẹ̀sìn Mùsùlùmí ṣùgbọ́n ó padà di ẹlẹ́ṣin kìrìsìtẹ́nì

Ní 2023 ó kẹ́kọ̀ọ́ gba ìmò oyè Báṣẹ́lọ̀ Degree ní HISTORY AND INTERNATIONAL RELATIONS Kogi State University, Nigeria

Iṣẹ orin àtúnṣe

Ọmọ ọdún mẹ́tàlá ni Adejo bẹ̀rẹ̀ orin ṣùgbọ́n ọdún 2014 ló bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin rẹ̀ ní pẹrẹwu Ó ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwo-orin ákọ́kọ́ rẹ̀ tí akọ́lẹ̀ TELL THE WORLD ní ọdún 2020 tí ó ní àwọn orin mẹ́wàá.

lẹ́hìn ọdún kan , ní Oṣù Kẹta ọdún 2021, Adejo ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwo-orin kejì rẹ̀ àti EP àkọ́kọ́ tí akole Orin Ọpẹ́ tí ó ní àwọn orin márùn-ún pẹ̀lú Eze Ebube àti Breathe On Me inclusive. [3]

Aworan aworan àtúnṣe

Àwọn àwo -orin àtúnṣe

Akọle Ọjọ Tu silẹ Awọn alaye
Nkankan bikose ihinrere Oṣu Kẹsan 2022
  • Ọna kika: Digital Download, Sisanwọle, CD
  • Nọmba awọn orin: 7
Awọn orin ti Ọpẹ (EP) Oṣu Kẹta ọdun 2021
  • Ọna kika: Digital Download, Sisanwọle, CD
  • Nọmba awọn orin: 5
Sọ fun agbaye Oṣu Kẹrin Ọjọ 2020
  • Ọna kika: Digital Download, Sisanwọle, CD
  • Nọmba awọn orin: 10
  • Mu kuro (2018)
  • Chinecherem (2019)
  • Onyenemema (2020)
  • Amin (2021)
  • Eze Ebube (2021)
  • Eze Ebube II (2022)
Odun Eye Ẹka Abajade Ref
Ọdun 2023 Eye Achievers Kingdom Gbàá [4]
Awọn akọle Gbàá
GX Awards style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé

Awọn itọkasi àtúnṣe