Nike Peller jẹ́ òṣèré èdè yorùbá ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà àtí oní ìrújú orí ìtàgé.[1][2] Ó jẹ́ ọmọ olóògbé Professor Peller, Nike jẹ́ olóyéYeye Agbasaga ti ìlú Erin Osun tí ó jẹ́ ní ọdún 2010.[3]

Àwọn eré tí ó ti ṣe àtúnṣe

  • Aye Lu
  • Adun
  • Eni Owo
  • Kiniun Alhaji
  • Àtànpàkò Otún
  • Sekere
  • Ayé Ajekú
  • Eko O'tobi
  • Fila Daddy
  • Tomisin

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

Àwọn Àjápọ̀ látìta àtúnṣe