Pascale Lamche (tí wọ́n bí ní Oṣù Keèje, Ọdún 1960) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdèFránsì àti Gúúsù Áfríkà. Ó gbajúmọ̀ fún dídarí àwọn eré tí ó lórúkọ bíi Stalingrad, Black Diamond, Pakistan Zindabad, French Beauty, Accused #1: Nelson Mandela, Sophiatown àti Winnie.[1] Ó tún maá n ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi ònkọ̀tàn àti olùyàwòrán eré.[2]

Pascale Lamche
Ọjọ́ìbíPascale Lamche
July 1960
Orílẹ̀-èdèFrench
Iṣẹ́Director, producer, writer, editor
Ìgbà iṣẹ́1997–present

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

Àwọn ìtakùn Ìjásóde àtúnṣe