STS-61-B jẹ́ iṣẹ́-àgbéṣe NASA tí ẹ̀tàlélógún ọkọ̀ inú-sánmà, ó sì tún jẹ́ èkejì ìlò ọkọ̀ inú-sánmà Atlantis. Wọ́n darí ọkọ̀ náà láti Kennedy Space Centre, Florida ní 26 oṣù kọkànlá 1985. Ní àkókò STS-61-B yìí, ẹgbẹ́ ọkọ̀ yìí fi irinṣẹ́ aṣèrànwọ́ àwọn ohun-èlò ìbánisọ̀rọ̀ lọ́wọ́ sípò, wọ́n sì tún dán àwọn ìlànà kíkọ́ nínú sánmà wò.

Irúfẹ́ àgbékalẹ inú-sánmà.

Àkókò ìgbéṣe: Ọjọ́ 6, wákàtí 21, ìṣẹ́jú 4, ìṣẹ́jú-àáyá 49 (aláṣeyọrí).

Itokasi àtúnṣe