Shelley Winters

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Shelley Winters (August 18, 1920 – January 14, 2006) jẹ óṣere lobinrin to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Shelley Winters
Ọjọ́ìbíShirley Schrift
(1920-08-18)Oṣù Kẹjọ 18, 1920
St. Louis
AláìsíJanuary 14, 2006(2006-01-14) (ọmọ ọdún 85)
Beverly Hills, California, U.S.
Resting placeHillside Memorial Park Cemetery
Orílẹ̀-èdèAmerican
Iléẹ̀kọ́ gígaThe New School
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1936–2006
Political partyDemocratic Party (United States)
Olólùfẹ́
  • Mack Paul Mayer
    (m. 1942; div. 1948)
  • Vittorio Gassman
    (m. 1952; div. 1954)
  • Anthony Franciosa
    (m. 1957; div. 1960)
  • Gerry DeFord (m. 2006)
Àwọn ọmọ1


Igbesi Aye Arabinrin naa àtúnṣe

Shelley Winters jẹ óṣere lobinrin ilẹ amẹrica ti iṣẹ rẹ lọ fun ọdun mẹwa lọnọ meje ti ó si ti yọju ni óriṣiriṣi èrè agbelewo.Shelley ni a bini Shirley Schrift ni St.Louis, ilẹ Missouri. Óṣere lobinrin naa jẹ ọmọ Rose (Akọrin ni St. Louis Municipal Opera Theatre) ati Jonas Schrift (Oluran àṣọ awọn ọkunrin) ti wọn si jẹ ijọ ẹlẹsin jew[2].

Shelley fẹ ọkọ lẹmẹrin;

  • Captain Mack Paul Mayer ni ọjọ 29, óṣu December ni ọdun 1948. Awọn mejeji pinya ni ọdun 1948[3].
  • Vittorio Gassman ni ọjọ 28, óṣu April ni ọdun 1952. Awọn mejeji pinya ni óṣu june ni ọdun 1954[3].
  • Anthony Franciosa ni ọjọ kẹrin, óṣu May ni ọdun 1957. Awọn mejeji pinya ni ọjọ 18, óṣu November ni ọdun 1960[4].
  • Gerry DeFord ni ọjọ mẹtala, óṣu January ni ọdun 2006[5].

Shelly Winters ku ni ọmọ ọdun marun lèèlogọrin ni ọjọ kẹrin óṣú january ni ọdun 2006 lórin aisan ọkan ni Rehabilitation Center ti Beverly Hills[6].

Ẹkọ àtúnṣe

Shelley lọsi ilè iwè jew ti ilẹ jamaica nibi ti arabinrin naa ti kọ orin hebrew. Óṣere lobinrin naa kọ èrè siṣè ni ilè iwè tuntun ni New York[7].

Ami Ẹyẹ Ati Idanilọla àtúnṣe

Ami Ẹyẹ Akademi

Ọdun Ipó Akọlè Èsi Ref(s)
1951 Ami Ẹyẹ Akadẹmi gẹgẹbi Óṣere lobinrin to dara ju A Place in the Sun Wọn yan [8]
1959 Ami Ẹyẹ Akademi gẹgẹbi Óṣere lobinrin to fun ni iran lọwọ julọ The Diary of Anne Frank pègèdè
1965 A Patch of Blue pègèdè
1972 The Poseidon Adventure Wọn yan

Ami Ẹyẹ Akademi Èrè Agbelewo ti Ilẹ British

Ọdun Ipó Akọlè Èsi Ref(s)
1972 Ami Ẹyẹ BAFTA gẹgẹbi Óṣere lobinrin to dara ju ninu ipó iranilọwọ The Poseidon Adventure Wọn yan [9]
1977 Next Stop, Greenwich Village Wọn yan

Ami Ẹyẹ ti Golden Globe

Ọdun Ipó Akọlẹ Èsi Ref(s)
1951 A Place in the Sun Wọn yan [10]
1959 The Diary of Anne Frank Wọn yan
1962 Ami Ẹyẹ ti Golden Globe gẹgẹbi Óṣere lobinrin lori Motion Picture – Drama Lolita Wọn yan
1966 rowspan=3 Alfie Wọn yan
1972 Pègèdè
1976 Next Stop, Greenwich Village Wọn yan

Ami Ẹyẹ Primetime Emmy

Ọdun Ipó Akọlè Èsi Ref(s)
1964 Ami Ẹyẹ Primetime Emmy gẹgẹbi Óṣere lobinrin to pegede julọ ninu Limited Series or Movie| rowspan=2|Bob Hope Presents the Chrysler Theatre Pègèdè [11]
1966 Wọn yan
1974 Óṣere lobinrin to ranilọwọ julọ ninu – Comedy/Drama Series McCloud NBC Sunday Mystery Movie Wọn yan

Itokasi àtúnṣe