Susan Kelechi Watson tí ó jẹ́ òṣèré Amẹ́ríkà àti ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kọkànlá oṣù Kọkànlá ọdún 1981. Ó di lààmì-laaka látàrí ipa rẹ̀ tí ó ma ń kó ní orí àwọn eré orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán Louie[1] àti ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn Beth Pearson nínú eré This Is Us. Wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ Critics' Choice Television Award for Best Supporting Actress in a Drama Series .

Susan Kelechi Watson
Watson at the 2017 Paleyfest
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kọkànlá 1981 (1981-11-11) (ọmọ ọdún 42)
Brooklyn, New York, U.S.
Ẹ̀kọ́Howard University (BFA)
New York University (MFA)
Iṣẹ́Òṣèré
Ìgbà iṣẹ́2004–present

Ìgbà èwe rẹ̀ àtúnṣe

Won bi Waston ni ilu Brooklyn ní ọjọ́ Kọkànlá oṣù Kọkànlá ọdún 1981.[2]Nígbà tí wọ́n bí àwọn òbí rẹ̀ mèjèjì náà sí orílẹ̀-èdè Jàmàíkà.[3] Orúkọ rẹ̀ "Kelechi" tí Watson's ń jẹ́ ṣàfihàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọmọ bíbí ẹ̀yà Ìgbò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó túmọ̀ sí Olúwa ṣeun.[citation needed] Watson obtained a Bachelor of Fine Arts degree from Howard University and a Master of Fine Arts degree from the Tisch School of the Arts Graduate Acting Program.[4]

Iṣẹ́ rẹ̀ àtúnṣe

Watson ti ń kópa ní orí eré àtìgbàdégbà Louie láti ọdún 2012 títí di ọdún 2014. Ó tún ń kópa nínú NCIS, The Following, àti The Blacklist. Ó tún kópa nínú eré oníṣe ti American Airlines Theatre ní ìlú New York, eŕe tí ọ̀gbẹ́ni Richard Greenberg kọ tí ọ pe àkòrí rẹ̀ ní A Naked Girl on the Appian Way ni odun 2005.[5] Ó ti ń kópa lórí eré oníṣe onípele àtìgbàdégbà ti This Is Us náà gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn Beth Pearson.[6]

Waston tún pẹ̀lú Tom Hanks kópa nínú eré tí Fred Rogers gbé jáde tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ A Beautiful Day in the Neighborhood ní ọdún 2019.[7]

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀ àtúnṣe

Ọdún Àkòrí eré Ipa tí ó kó Notes
2004 Hack Paula Episode: "Extreme Commerce"
2004 The Jury Andrea Davis Episode: "Lamentation on the Reservation"
2004–2005 Third Watch Emma St. Claire 12 episodes
2005 Law & Order: Trial by Jury Jill Tolbert Episode: "Blue Wall"
2007 Medium Subordinate Episode: "Joe Day Afternoon"
2007 Kidnapped Elle King 3 episodes
2007 Private Practice Beth O'Brien Episode: "In Which Sam Receives an Unexpected Visitor..."
2007 Alibi Genevieve Egan Television movie
2007–2008 NCIS NCIS Intel Analyst Nikki Jardine 3 episodes
2008 Numb3rs Nina Hunter Episode: "Pay to Play"
2004, 2009 Law & Order Tanya Ware / Thea Curry Episodes: "Can I Get a Witness?", "The Drowned and the Saved"
2010 Futurestates Tia Episode: "Tia & Marco"
2011 Eden Det. Monica Lopez Episode: Pilot
2011 The Good Wife Lauryn Fisher Episode: "What Went Wrong"
2013 Golden Boy April McGee Episode: "Vicious Cycle"
2014 And, We're Out of Time Diana Television film
2012–2014 Louie Janet 12 episodes
2014 Royal Pains Naomi Episode: "I Did Not See That Coming"
2013–2016 The Blacklist Ellie 4 episodes
2014 The Following Cindy 3 episodes
2015 Blue Bloods Detective Episode: "Sins of the Father"
2015 Veep Sue's friend Episode: "Election Night"
2015 Happyish Sandy Episode: "Starring Rene Descartes, Adweek and HRH the Princess of Arendelle"
2016 Billions Wilma 'Billie' Keen Episode: "YumTime"
2016 Limitless Elo Episode: "Fundamentals of Naked Portraiture"
2016–present This Is Us Beth Pearson Main role
2016 Divorce Victoria Tuckson Episode: "Counseling"
2019 A Beautiful Day in the Neighborhood Andrea Vogel
2021 Rumble (voice)

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

Ìtàkùn ìjásóde àtúnṣe

Àdàkọ:ScreenActorsGuildAwards EnsembleTVDrama 2010–2019 Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:US-screen-actor-1980s-stub