Vanessa Redgrave je ọmọ óṣèrè lọkunrin Sir Michael Regrave ati óṣèrè lobinrin Rachel Kempson ti a bini ọjọ ọgbọn óṣu January ni ọdun 1937[1]. Arabinrin naa jẹ osere to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[2].

Dame
Vanessa Redgrave
Order of the British Empire
Vanessa Redgrave
Redgrave at the 2016 Cannes Film Festival
Ọjọ́ìbí30 Oṣù Kínní 1937 (1937-01-30) (ọmọ ọdún 87)
Blackheath, London
Ẹ̀kọ́The Alice Ottley School]], Worcester, England
Iléẹ̀kọ́ gígaRoyal Central School of Speech and Drama
Iṣẹ́
  • Actress
  • political activist
Ìgbà iṣẹ́1958–present
Notable workList of Vanessa Redgrave performances
Olólùfẹ́
  • Tony Richardson]]
    (m. 1962; div. 1967)
  • Franco Nero (m. 2006)
Alábàálòpọ̀Timothy Dalton (1971–1986)
Àwọn ọmọ
  • Natasha Richardson
  • Joely Richardson
  • Carlo Gabriel Nero
Parent(s)
  • Michael Redgrave
  • Rachel Kempson
ẸbíRedgrave family
AwardsList of awards and nominations received by Vanessa Redgrave

Igbesi Aye Arabinrin naa àtúnṣe

Vanessa kẹkọ ni ilè iwè tadalẹ fun awọn ọmọ obinrin; Ile ẹkọ Alice Ottley ni Worcester ati Ilẹ ẹkọ Queen's Gate.Vanessa wọ ile iwe sisọ ọrọ ati drama ni ọdun 1954. Óṣere lobinrin naa kọkọ jade si òju èrè West End fun igba akọkọ ni ni ọdun 1958[3]. Óṣere naa fẹ adari ere Tony Richardson lati 1962 ti wọn si bi ọmọbinrin meji; Natasha ati Joely to di óṣèrè lobinrin[4]. Vanessa ati Ruchardson pinya ni ọdun 1967.

Ami Ẹyẹ ati Idani lọla àtúnṣe

  • Vanessa gba ami ẹyẹ telivision academy ti british, ami ẹyẹ Golden Globe ati ami ẹyẹ meji ti Primetime Emmy[5][6].

Itokasi àtúnṣe