Àìsàn ẹ̀jẹ̀ ríru

Àìsàn ẹ̀jẹ̀ ríru (HTN tàbí HT), a tún lè pè ní ẹ̀jẹ̀ gbígbóná tàbí HBP, ni ó jẹ́ àìsàn tí ó ma ń lọ tí ó ń bọ̀ nínú àgọ́ ara fún ìgbà pípẹ́, nígbà tí ẹ̀jẹ̀ inú iṣan ọkàn ń lọ tàbí ru sókèju bí ó ti yẹ lọ ní gbogbo ìgbà[1].[2] Ẹ̀jẹ̀ ríru kìí sábà ń fúni ní àmì kí ó tó bẹ̀rẹ̀.[3] Bí ẹ̀jẹ̀ ríru bá ṣe pẹ́ sí nínú ara ni ó sábà ma ń fa àìsàn rọpá-rọsẹ̀, àrùn ọkàn, Ìdaṣẹ́sílẹ̀ ọkàn, ojú fífọ́ ,àìsàn kídìnrín àti àrùn ọpọlọ. [4][5][6][7]

Ohun tí ó ń fa ẹ̀jẹ̀ ríru ati itọ́jú rẹ̀ àtúnṣe

Ẹ̀jẹ̀ ríru tàbí ìfúnpá gíga ni a lè pin sí ọ̀nà méjì. Akọ́kọ́ ni

  • ẹ̀jẹ̀ ríru kékeré,
  • ẹ̀jẹ̀ ríru ńlá. [8] About 90–95% of cases are primary, defined as high blood pressure due to nonspecific lifestyle and genetic factors.[8][9]Àwọn ohun tí ó le ṣokùnfà kí ènìyàn ó ní àisàn ẹ̀hẹ̀ ríru ni
  1. àpọ̀jù iyọ̀ nínú ohun jíjẹ wa,
  2. ara àìsàn
  3. mímu sìgá tàbí ohun tí ó je mọ́ ohun mì mú bẹ́ẹ̀.
  4. mímu ọtí líle ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[3][8]àwọn márù un tó kú lára àwọn ohun tí ó ṣokùnfà àìsàn ẹ̀jé ríru ni a lè kin sí abẹ́ ẹjẹ̀ ríru ńlá ní èyí tí a ti lè ri àrùn Kíndìnrín tí ó lè mú kí iṣan inú ọkàn tínrín. [8]

Bí a ṣe ń ṣàyẹ̀wò rẹ̀ àtúnṣe

Ọ̀nà méjì ni wọ́n ma ń gbà ṣe ayẹ̀wò àìsàn yí, àwọn ni

  1. systolic ìlànà kékeré ati
  2. diastolic ìlànà ńlá.[3].

Àwọn ìtọ́ka sí àtúnṣe

  1. "Hypertension". World Health Organization (WHO). 2019-06-20. Retrieved 2024-04-14. 
  2. Naish, Jeannette; Court, Denise Syndercombe (2014). Medical sciences (2 ed.). pp. 562. ISBN 9780702052491. https://books.google.com/books?id=K21_AwAAQBAJ. 
  3. 3.0 3.1 3.2 "High Blood Pressure Fact Sheet". CDC. 19 February 2015. Archived from the original on 6 March 2016. Retrieved 6 March 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Global burden of cardiovascular disease and stroke: hypertension at the core". The Canadian Journal of Cardiology 31 (5): 569–71. May 2015. doi:10.1016/j.cjca.2015.01.009. PMID 25795106. 
  5. Mendis, Shanthi; Puska, Pekka; Norrving, Bo (2011). Global atlas on cardiovascular disease prevention and control (1st ed.). Geneva: World Health Organization in collaboration with the World Heart Federation and the World Stroke Organization. pp. 38. ISBN 9789241564373. http://whqlibdoc.who.int/publications/2011/9789241564373_eng.pdf?ua=1. 
  6. "Treatment options and considerations for hypertensive patients to prevent dementia". Expert Opinion on Pharmacotherapy 18 (10): 989–1000. July 2017. doi:10.1080/14656566.2017.1333599. PMID 28532183. 
  7. "Modifiable Risk Factors and Atrial Fibrillation". Circulation 136 (6): 583–596. August 2017. doi:10.1161/CIRCULATIONAHA.116.023163. PMID 28784826. 
  8. 8.0 8.1 8.2 8.3 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Lancet2015
  9. "Essential hypertension. Part I: definition and etiology". Circulation 101 (3): 329–35. January 2000. doi:10.1161/01.CIR.101.3.329. PMID 10645931.