Àjọ Ìlera Àgbáyé jẹ́ àjọ United Nation tí wọ́n dá sílẹ̀ fún ètò ìlera gbogbo àgbáyé. Wọ́n dáa sílẹ̀ ní Ọjọ́ keje Oṣù kẹrin Ọdún 1948, olú ilé iṣẹ́ rẹ̀ wà ní Geneva, Switzerland.[1].[2]


Àjọ Ìlera Àgbáyé
Flag of WHO.svg
Àsíá Àjọ Ìlera Àgbáyé
Irú àjọ United Nation
Orúkọkúkúrú WHO
OMS
Olórí Margaret Chan, Alákóso
Ipò Active
Dídásílẹ̀ Oṣù Kẹrin 7, 1948; ọdún 71 sẹ́yìn (1948-04-07)
Ibùjókòó Geneva, Switzerland
Ibiìtakùn who.int
Òbí United Nations Economic and Social Council (ECOSOC)

Àwọn ìtọ́kasí ItokasiÀtúnṣe

  1. "World Health Organization". The British Medical Journal (BMJ Publishing Group) 2 (4570): 302–303. 7 August 1948. doi:10.1136/bmj.2.4570.302. JSTOR 25364565. 
  2. Sze Szeming Papers, 1945–2014, UA.90.F14.1, University Archives, Archives Service Center, University of Pittsburgh.