Àrùn Parkinson
Àrùn Parkinson jẹ́ ààrùn ọpọlọ tí ó ní ṣe pẹ̀lú ẹ̀yà ọpọlọ tí ó rọ̀mọ́ bí ènìyàn ṣe ń rìn.[1] Ààrùn yìí mà ń fara hàn díè díẹ̀ ni.[1] Ní ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ ààrún yìí, oun tí a máa ń sábà rí ni kí ara máa gbọ̀n, kí ó máa le kakaraka, kí ènìyàn má lè rìn dáradára.[1] Èyí lè jẹ́ kí ìrònú àti àwọn oríṣiríṣi ìwà wáyé. Ó wọ́pọ̀ láàrín àwọn ọkùnrin ju obìrin lọ.[1]
Parkinson's disease Classification and external resources | |
Àfihàn ààrùn Parkinson tí Sir William Richard Gowers gbéjáde láti A Manual of Diseases of the Nervous System ní ọdún 1886 | |
ICD-10 | G20., F02.3 |
ICD-9 | 332 |
DiseasesDB | 9651 |
MedlinePlus | 000755 |
eMedicine | neuro/304 neuro/635 láàrín àwọn ọmọdé pmr/99 rehab |