Ìjọba ìbílẹ̀ Ọ̀jọ́

Ìjọba Ìbílẹ̀ Ọjàọ́ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tí lórúkọ jùlọ ní ìpínlẹ̀ Èkó, tí ó wà nínú ìlú Ọ̀jọ́ ní ìpínlẹ̀ Èkó, ibẹ̀ sì ni Fásitì ìpínlẹ̀ Èkó wà. [2] Ìlú Ọ̀jọ́ wà ní apá ìwọ̀ Oòrùn ìpínlẹ̀ Èkó, ní òpópónà márosẹ̀ tí ó lọ sí ìlú Àgbádárìgì. Ìlú Ọ̀Jljọ́ jẹ́ ibùgbé fún tonílé tàlejò, tí ọjà oríṣiríṣi bi ọjà Gbogbo-gbò Alábà, Alábà Ràgó, ọjà Ìpàtẹ Okòwò Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀, ọjà Ìyànà-Ìbá àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ sì gúnwà síbẹ̀

Ọ̀jọ́
LGA and town
Ojo shown within the State of Lagos
Ojo shown within the State of Lagos
Ọ̀jọ́ is located in Nigeria
Ọ̀jọ́
Ọ̀jọ́
Ojo shown within the State of Lagos
Coordinates: 6°28′N 3°11′E / 6.467°N 3.183°E / 6.467; 3.183Coordinates: 6°28′N 3°11′E / 6.467°N 3.183°E / 6.467; 3.183
Country Nàìjíríà
StateÌpínlẹ̀ Èkó
Founded byÈṣùgbèmí (from Àwórì subgroup of the Yorùbá [1])
Government
 • Ọlọ́jọ́Adéníyí Rufai
 • Local government ChairmanYínká Dúrósinmí
Area
 • Total70 sq mi (182 km2)
Population
 (2006 census)
 • Total609,173
 • Density8,700/sq mi (3,300/km2)
Time zoneUTC+1 (WAT)

Ìtàn Ìṣẹ̀dálẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe

Ìtàn àtẹnudẹ́nu fi hàn wípé Èṣùgbèmí, ìyàwó rẹ̀ Erelú àti Olúwo Òṣú tí wọ́n wá láti Ilé-Ifẹ̀ láti dá ìlú tí wọn yóò ma pè ní Ìlúfẹ̀ ni wọ́n tẹ ìlú Ọ̀jọ́. Èṣùgbèmí tí ó jẹ́ Ọdẹ ni gbèrò láti ta ìlúfẹ̀ t í ó di Ọ̀jọ́ lónìí ni ó rí agbègbè irà ni ó sọ fún Olúwo rẹ̀ Òṣú tí eyan náà sì gbéfá janlẹ̀ ní Ìkémọ tí ó di Àfin ti Ọlọ́jọ̀ọ́ lónìí. [3] Ìtẹ̀síwájú àti ìdàgbàsókè ìlú yí ni ó mú kí p7pọ̀ nínú àwọn ènìyàn Àwórì, àwọn ènìyàn Ìdó àti Ìdúmọ̀tà tí ó tẹ ìlú Irewe Osólú dó wá tí wọ́n sì ń bá wọn gbé pọ̀. [4]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe