Ìpínlẹ̀ Rivers

Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà

Ìpínlẹ̀ Rivers tí a tún mọ̀ bíi Rivers, ni ìkan nínú àwọn ìpínlẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà 36. Gẹ́gẹ́ bí dátà ìkanìyàn tó jáde ní ọdún 2006 ṣe fihàn, ìpínlẹ̀ náà ní iye ènìyàn 5,198,716, èyí sọ ọ́ di ìpínlẹ̀ tó ní iye èniyàn púpọ̀jùlọ kẹfà ní Nàìjíríà.[5] Olúìlú àti ìlú tótóbijùlọ rẹ̀ ni Port Harcourt. Ìlú Port Harcourt ní Nàìjíríà gẹ́gẹ́bí gbọ̀ngàn àwọn ilé-iṣẹ́ epo. Ìpínlẹ̀ Rivers jámọ́ Òkun Atlantiki ní gúúsù, ó ní bodè mọ́ àwọn ìpínlẹ̀ Imo and Abia ní àríwá, ìpílẹ̀ Akwa Ibom ní ìlàòrùn, àti àwọn ìpínlẹ̀ Bayelsa àti Delta ní ìwọ̀òrùn. Ìpínlẹ̀ Rivers ní ọ̀pọ̀ ẹ̀yà tí nínú wọn ni: àwọn Ikwerre, àwọn Ijaw, àwọn Ògóni àti àwọn ẹ̀yà púpọ̀ míràn. Orúkọ fún àwọn ará ìpínlẹ̀ yìí ni "Riverians" tàbi "àwọn ará Rivers".[6][7]

Ìpínlẹ̀ Rivers
Official seal of Ìpínlẹ̀ Rivers
Seal
Nickname(s): 
Location of Rivers State in Nigeria
Location of Rivers State in Nigeria
Coordinates: 4°45′N 6°50′E / 4.750°N 6.833°E / 4.750; 6.833Coordinates: 4°45′N 6°50′E / 4.750°N 6.833°E / 4.750; 6.833
Orílẹ̀-èdè Nigeria
Geopolitical zoneSouth South
Formation27 Oṣù Kàrún 1967 (1967-05-27) (55 years ago)
OlúìlúPort Harcourt
LGAsÀdàkọ:Comma separated entries
Government
 • BodyGovernment of Rivers State
 • Gómìnà[2]Ezenwo Wike (PDP)
 • DeputyIpalibo Banigo (PDP)
 • LegislatureHouse of Assembly
Area
 • Total11,077 km2 (4,277 sq mi)
Area rank26th
Population
 (2006 Census)
 • Total5,198,716[1]
 • Rank6th
 • Density635.89/km2 (1,646.9/sq mi)
Demonym(s)Riverian
GDP (PPP)
 • Year2007
 • Total$21.07 billion[3]
 • Per capita$3,965[3]
Time zoneUTC+01 (WAT)
postal code
500001
ISO 3166 codeNG-RI
HDI (2018)0.642[4]
medium · 6th of 37
Websiteriversstate.gov.ng

Apá inú ìpínlẹ̀ náà jẹ́ ẹgàn tútù olóoru; ní towards the coast, the typical Niger Delta environment features many mangrove swamps.

HistoryÀtúnṣe

Territory and statusÀtúnṣe

Rivers State, named after the many rivers that border its territory, was part of the Oil Rivers Protectorate from 1885 till 1893 when it became part of the Niger Coast Protectorate. In 1900, the region was merged with the chartered territories of the Royal Niger Company to form the colony of Southern Nigeria. The state was formed in 1967 with the split of the Eastern Region of Nigeria. In 1996 the state lost territory to form Bayelsa State.Àwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. "2006 PHC Priority Tables – NATIONAL POPULATION COMMISSION". population.gov.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-10-10. 
  2. See List of Governors of Rivers State for a list of prior governors
  3. 3.0 3.1 "C-GIDD (Canback Global Income Distribution Database)". EIU Canback. Retrieved 2008-08-20. 
  4. "Sub-national HDI - Area Database - Global Data Lab". hdi.globaldatalab.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-09-13. 
  5. "Nigeria: Administrative Division". City Population. Retrieved 28 November 2014. 
  6. "Amaechi Catches Facebook Bug". Daily Independent, accessed via HighBeam Research Àdàkọ:Subscription. 10 August 2009. Archived from the original on 6 July 2017. Retrieved 27 February 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Rivers State government website". Retrieved December 7, 2010.