Ọ̀sẹ̀ kan je ọjọ́ meje ninu kàlẹ́ndà Giringori. Awon ojo wonyi ni ede yoruba ni a mo si: Ojo-Aje, Ojo-Isegun, Ojoru, Ojobo, Ojo-Eti, Ojo-Abameta, Ojo-Aiku. Ọ̀sẹ je eyo àsìkò ti o tobi ju ọjọ́ kan lo sugbon ti o kere ju osù kan lo.

Weekday heptagram used for the planets or the days of the weekItokasiÀtúnṣe