Ọmọlẹ́yìn (ní Kristẹni)

Ní àwùjọ Kristẹni, ọmọlẹ́yìn ni àwọn tí ó ti pinu láti tẹ̀lẹ́ Jesu. Wọ́n lo ọ̀rọ̀ yìí ní majẹmu titun nínú àwọn ìwé Ìhìn Rere àti ìwé ìṣe àwọn Àpọ́sítélì

Ní ayé àtijó, ọmọlẹ́yìn jẹ́ ẹni tí ó ti pinu láti tẹ̀lé olùkọ́ rẹ̀. Ọmọlẹ́yìn yàtò sí akẹ́kọ̀ọ́. Ọmọlẹ́yìn nínú Bíbélì jẹ́ ẹni tí ó ń ṣe àfarawé ayé àti ẹ̀kọ́ olùkọ́ rẹ̀, ó yàtọ̀ sí akẹ́kọ̀ọ́ tí ń ṣe àfarawé ayé olùkọ́ rẹ̀.[1] Ó jé ìkẹ́kọ́ láti ọ̀dọ̀ olùkọ́ èrò láti mú kí ayé akẹ́kọ̀ọ́ dàbí ti olùkọ́ tàbí ọ̀gá rẹ̀.[2]

Majẹmu titun sọ nípa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọlẹ́yìn Jesu nígbà iseranse rẹ̀.

Jésù ń bá àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ ṣòro (John 14-17), lẹyìn oúnjẹ àlè Olúwa igbẹyin Jesu pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀.

Àwọn Ìtókasí àtúnṣe

  1. Köstenberger, Andreas J. (1998). "Jesus as Rabbi in the Fourth Gospel". Bulletin for Biblical Research 8: 97–128. doi:10.5325/bullbiblrese.8.1.0097. https://biblicalstudies.org.uk/pdf/bbr/rabbi_kostenberger.pdf. 
  2. Sri, Edward (2018). "In the Dust of the Rabbi: Clarifying Discipleship for Faith Formation Today". The Catechetical Review Issue #4.2: online edition. https://review.catechetics.com/dust-rabbi-clarifying-discipleship-faith-formation-today.