Adams Oshiomhole


Adams Oshiomhole (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù kẹrin ọdún 1952) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ẹ̀dó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni Alága ẹgbẹ́ òṣèlú-ṣèjọba tí All Progressives Congress APC.[1] Oshiomhole ti fìgbà kan jẹ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ Ẹ̀dó láti ọdún 2008 sí ọdún 2016 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú Action Congress of Nigeria.[2] Kí ó tó di àkókò yìí, òun ni Alága ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́,NLC lorílẹ̀ èdè Nàìjíríà nígbà ìṣèjọba Ààrẹ àná, Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́.[3]

Adams Aliyu Oshiomhole
AdamsOshiomhole.jpg
Adams Oshiomhole, former President of the Nigeria Labour Congress (right) with U.S. Ambassador to Nigeria Howard F. Jeter (center), 5 July 2002, Lagos.
National Chairman of the All Progressives Congress
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
24 July 2018
Governor of Edo State
In office
12 November 2008 – 12 November 2016
AsíwájúOserheimen Osunbor
Arọ́pòGodwin Obaseki

Àwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. "APC Affirms Oshiomhole As New National Chairman". Channels Television. 2018-06-23. Retrieved 2019-12-08. 
  2. "Nigeria Governors’ Forum". Nigeria Governors' Forum. Retrieved 2019-12-08. 
  3. "Profile: Adams Oshiomhole". BBC NEWS. 2004-10-13. Retrieved 2019-12-08. 

ItokasiÀtúnṣe