Adetokunbo Ademola
Onigbejo naijiriya
Adetokunbo Adegboyega Ademola, KBE, GCON (1 February 1906 - 29 January 1993) jẹ́ adájọ́ àgbà ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ adájọ́ àgbà ile Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí , àti ọmọ Ọba Ladapo Ademola II, tí ó jẹ́ Aláké ti Ẹ̀gbá tẹ́lẹ̀.[1] [2]
Adetokunbo Ademola | |
---|---|
Olùdájọ́ Àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà 2k | |
In office 1958–1972 | |
Asíwájú | Stafford Foster-Sutton |
Arọ́pò | Taslim Olawale Elias |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1 Oṣù Kejì 1906 |
Aláìsí | 29 January 1993 | (ọmọ ọdún 86)