Aisha Abubakar Abdulwahab

Dr. Aisha Abubakar Abdulwahab (tí a bí ní ọdún 1971) jẹ́ ọlọ́pá ọmọ orílẹ̀-èdè NàìjíríàUNESCO fún ní ẹ̀bùn owó láti ṣe ìwádìí nípa ààrùn ikó ààrùn Tuberculosis.

Aisha Abubakar Abdulwahab
Ọjọ́ìbíỌdún 1971
Orílẹ̀-èdèỌmọ orílẹ̀-ẹ̀dẹ̀ Nàìjíríà
Gbajúmọ̀ fúnproposing novel research to study tuberculosis
Àwọn ọmọMéjì

Ayé rẹ̀ àtúnṣe

A bí Aisha Abubakar Abdulwahab ní ọdún 1971 ó sì dara pọ̀ mọ́ egbé ọlọ́pá Nàìjíríà ní ọdún 1995. Ó ní àmì ẹyẹ nínú ìmò veterinary science.[1]

Ní ọdún 2005, UNESCO fun ní ẹ̀bùn owó fún àbá rẹ̀ láti fi DNA wádìí ǹkan tó pa ààrùn tuberculosis tó ń pa ènìyàn lára àti èyí tó ń pa màlúù lára. Ó ní pé tó n bá gba omi lára ènìyàn àti lára màlúù, òun le mọ bí àwọn ọmọ Nàìjíríà ṣe ń kọ́ àìsàn nípa mí mu omi oyàn màálù tí wọn kò tí sè.[2] UNESCO fun ní ẹ̀bùn owó náà láti parí ìwádìí rẹ̀ ní Yunifásitì tí ó bá fẹ́. Adbulwahab ní ọkọ àti ọmọ méjì.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 Female cop bags UNESCO award Archived 2016-03-04 at the Wayback Machine., 2005, OnlineNigeria, Retrieved 8 February 2016
  2. Science needs women, UNESCO.org, Retrieved 9 February 2016