Albáníà

(Àtúnjúwe láti Albania)

Albáníà (Gbígbọ́i /ælˈbniə/ al-BAY-nee-ə, Àdàkọ:Lang-sq, Gheg Albanian: Shqipnia/Shqypnia), lonibise bi Orileominira ile Albáníà (Àdàkọ:Lang-sq, pipe Àdàkọ:IPA-sq; Gheg Albanian: Republika e Shqipnísë), je orile-ede ni Guusuilaorun Europe, ni agbegbe awon Balkani. O ni bode mo Montenegro ni ariwailaorun, Kosovo[a] ni riwailaorun, Orileominira ile Makedonia ni ilaorun ati Girisi ni gusu ati gusuilaorun. O ni eti-omi ni egbe Omi-okun Adriatiki ni iwoorun, ati legbe Omi-okun Ionia ni gusiiworun. O fi iye to din ni 72 km (45 mi) jinna si Italy, nikoja Strait of Otranto to ja Adriatic Sea po mo Ionian Sea. Albáníà je omo egbe UN, NATO, Agbajo fun Abo ati Ifowosowopo ni Europe, Igbimo ile Europe, Agbajo Owo Agbaye, Agbajo Ipade Onimale be sini omo egbe lati ibere Isokan fun Mediteraneani. Albania ti fe di omo egbe Isokan Europe lati January 2003, be sini o ti toro lati di omo egbe lati 28 April 2009.[9]

Orílẹ̀òmìnira ilẹ̀ Albáníà
Republic of Albania
Republika e Shqipërisë
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè[Himni i Flamurit] error: {{lang}}: text has italic markup (help)  
Hymn to the Flag

Ibùdó ilẹ̀  Albáníà  (green) on the European continent  (dark grey)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Albáníà  (green)

on the European continent  (dark grey)  —  [Legend]

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Tirana
41°20′N 19°48′E / 41.333°N 19.8°E / 41.333; 19.8
Èdè àlòṣiṣẹ́ Albanian1
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn  92% Albanians,
6% Greeks,[1][2] 2% others[3]
Orúkọ aráàlú Ará Albáníà
Ìjọba Orílẹ̀òmìnira oníléaṣòfin
 -  Ààrẹ Ilir Meta
 -  Alákóso Àgbà Edi Rama
Formation
 -  Principality of Arbër 1190 
 -  League of Lezhë 2 March 1444 
 -  Independence from the Ottoman Empire 28 November 1912 
 -  Recognized by the Great Powers 2 December 1912 
 -  Current Constitution 28 November 1998 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 28,748 km2 (143rd)
11,100 sq mi 
 -  Omi (%) 4.7
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2010 3,195,000 [4] (136th)
 -  2001 census 3,069,275 [5] 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 111.1/km2 (63)
327.8/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2010
 -  Iye lápapọ̀ $23.864 billion[6] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $7,453[6] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2010
 -  Àpapọ̀ iye $11.773 billion[6] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $3,677[6] 
Gini (2005) 26.7[7] (low
HDI (2010) 0.719[8] (high) (64th)
Owóníná Lek (ALL)
Àkókò ilẹ̀àmùrè CET (UTC+1)
 -  Summer (DST) CEST (UTC+2)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .al
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 355
1 Greek, Macedonian and other regional languages are government-recognized minority languages.

Albáníà je oseluarailu onileasofin pelu itokowo toun yipada. Oluilu Albáníà, Tirana, je ile fun awon eniyan bi 600,000 ninu awon eniyan 3,000,000 to wa lorile-ede na.[10] Atunse oja alominira ti si orile-ede sile fun inawo idagbasoke latokere, agaga fun idagbasoke okun ati eto irinna.[11][12][13]ItokasiÀtúnṣe

 1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named IJ
 2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named JP
 3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named cia
 4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named instat2010
 5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named 2001census
 6. 6.0 6.1 6.2 6.3 "Albania". International Monetary Fund. Retrieved 12 April 2011. 
 7. "Distribution of family income – Gini index". The World Factbook. CIA. Archived from the original on 23 July 2010. Retrieved 1 September 2009. 
 8. "Human Development Report 2010" (PDF). United Nations. 2010. Retrieved 5 November 2010. 
 9. "Albania applies for EU membership". BBC News. 28 April 2009. http://news.bbc.co.uk/2/hi/europe/8023127.stm. Retrieved 29 April 2009. 
 10. CIA – The World Factbook Àdàkọ:WebCite
 11. Reports: Poverty Decreases In Albania After Years Of Growth.Dow Jones Newswires, 201-938-5500. Nasdaq.com
 12. Albania plans to build three hydropower plants.People's Daily
 13. Strong GDP growth reduces poverty in Albania-study. Reuters. Forbes.com