Boerewors jẹ́ oúnjẹ ti ilẹ̀ adúláwọ̀ tó gbajúmọ̀ ní apá Gúúsù Áfríkà. Wọn a máa pèlò rẹ̀ pẹ̀lú lílọ ẹran màlúù àti ti ẹlẹ́dẹ̀ àti ti àgùntàn, èyí tí wọn ó ra róbóróbó síwáju kí wọ́n tó din nínú epo. Ó maá n pẹ̀lú oríṣiríṣi èrònjà, wọ́n sì maá n fi mu ẹ̀kọ.