Daniel Lebern Glover ( /ˈɡlʌvər/; ọjọ́ìbí July 22, 1946) ni òṣeré, olùdarí fílmù, àti alákitiyan ọ̀ṣèlú ará Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ìṣeré rẹ̀ bíi Roger Murtaugh nínú àwọn fílmù Lethal Weapon. Ó ṣeré nínú àwọn fílmù bíi The Color Purple (1985), To Sleep with Anger (1990), Predator 2 (1990), Angels in the Outfield (1994) àti Operation Dumbo Drop (1995). Glover tún kópa nínú àwọn fílmù bíi Silverado (1985), Witness (1985), Saw (2004), Shooter (2007), 2012 (2009), Death at a Funeral (2010), Beyond the Lights (2014), Dirty Grandpa (2016), àti Sorry to Bother You (2018). Glover jẹ́ alákitiyan ọ̀rọ̀ ọ̀ṣèlú.

Danny Glover
Danny Glover 2014.jpg
Glover in 2014
Ọjọ́ìbíDaniel Lebern Glover
Oṣù Keje 22, 1946 (1946-07-22) (ọmọ ọdún 75)
San Francisco, California, U.S.
Orílẹ̀-èdèAmerican
Iṣẹ́Actor, director, activist
Ìgbà iṣẹ́1978–present
Olólùfẹ́
  • Asake Bomani
    (m. 1975; div. 2000)
  • Eliane Cavalleiro
    (m. 2009)
Àwọn ọmọ1
Websitelouverturefilms.com

Ìgbà èweÀtúnṣe

Wọ́n bí Glover ní ìlú San Francisco, ìyá rẹ̀ ni Carrie (Hunley) àti bàbá rẹ̀ ni James Glover.[1]

ItokasiÀtúnṣe

  1. "Augusta area tied to celebrities". Chronicle.augusta.com. Archived from the original on January 29, 2016. Retrieved July 31, 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)