David Harold Blackwell tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹrin ọdún 1919, tí ó ṣaláìsí ní ọdún 2010 jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Statistiki ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifasity Kalifornia ní Berkeley, bẹ́é sì ni orúkọ rẹ̀ wà lára àwọn aropojinle Rao-Blackwell. Wọ́n bi ní agbègbè Centralia, ní ìlú Illinois. Ó tún jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àti Nàìjíríà tí ó kọ́kọ́ di ìkan lára àwọn Akademi Olomoorile-ede ninu Sayensi, àti Adúláwọ̀ akọ́kọ́ tó kọ́kọ́ di adarí ẹ̀kọ́ ní ẹ̀ka ẹ̀kọ́ UC Betkeley. [1][2]

David Blackwell
David Harold Blackwell
Ìbí(1919-04-24)Oṣù Kẹrin 24, 1919
Centralia, Illinois,
United States
AláìsíJuly 8, 2010(2010-07-08) (ọmọ ọdún 91)[1]
Berkeley, California
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerican
PápáMathematician
Ilé-ẹ̀kọ́University of California, Berkeley
Ibi ẹ̀kọ́University of Illinois at Urbana-Champaign
Doctoral advisorJoseph Leo Doob
Notable studentsRoger J–B Wets
Ó gbajúmọ̀ fúnRao–Blackwell theorem
Blackwell channel

Iṣẹ́ rẹ̀ àtúnṣe

Ní ọdún 1935, nigba to je omo odun 16, Blackwell lo si Yunifasiti Illinois ni Urbana-Champaign pelu ero lati di oluko mathimatiki ni ile-eko alakobere. Ni 1938 o gba iwe-eri bachelor ninu mathimatiki, iwe-eri master ni 1939, be sini o di dokita ninu mathimatiki ni 1941 nigba to je omo odun 22, gbogbo won lati Yunifasiti Illinois.[3][4]



Itokasi àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 Sorkin, Michael (July 14, 2010). "David Blackwell fought racism; become world-famous statistician". Saint Louis Post-Dispatch. http://www.stltoday.com/news/local/obituaries/article_8ea41058-5f35-5afa-9c3a-007200c5c179.html. 
  2. Cattau, Daniel (July 2009). "David Blackwell 'Superstar'". Illinois Alumni (University of Illinois Alumni Association): pp. 32–34. 
  3. James H. Kessler, J. S. Kidd, Renee A. Kidd. Katherine A. Morin (1996), Distinguished African American Scientists of the 20th Century, Greenwood, ISBN 0897749553 
  4. Grime, David (July 17, 2007). "David Blackwell, Scholar of Probability, Dies at 91". New York Times. http://www.nytimes.com/2010/07/17/education/17blackwell.html. Retrieved August 22, 2010.