Giorgos tabi George Seferis (Γιώργος Σεφέρης) ni orúkọ ìnagijẹ Geōrgios Seferiádēs (Γεώργιος Σεφεριάδης, 13 March [O.S. 29 February] 1900 - September 20, 1971). Òhun ni olùkọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè Greece tó ṣe pàtàkìjùlọ ní bíi ogún ọrundún sẹ́yìn, tí ó gba ẹbun Nobel. Ó tún ṣisẹ́ bíi aṣojú orílẹ̀ èdè rẹ̀ ní Greek Foreign Service, kí wọ̣́n tó yànhán gẹ́gẹ́ bí asojúUK, ibi tó wà lati ọdún 1957 sí 1962.

Giorgos Seferis
180px
Iṣẹ́Poet, Diplomat
Ọmọ orílẹ̀-èdèGreek
Notable awardsNobel Prize in Literature
1963

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe