Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun

Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà
(Àtúnjúwe láti Ipinle Osun)

Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn Ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun jẹ́ Ìpínlẹ̀ tí ó wà ní àárín gbùngbùn apá Ìwọ̀-Oòrùn Gúúsù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní Ìlú Òṣogbo. Ó ní ibodè ní àríwá mọ́ Ipinle Kwara, ní ìlà-oòrùn díẹ̀ mọ́ Ipinle Ekiti àti díẹ̀ mọ́ Ipinle Ondo, ní gúúsù mọ́ Ipinle Ogun àti ní ìwọ̀oòrùn mọ́ Ipinle Oyo. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí ni Gómìnà Gboyega Oyetola .[2] Wọ́n dìbò yàn-án wọlé ní 2018.[3] Ọsun ní ibi tí ọ̀pọ̀ àwọn ibi mèremère tó gbajúmọ̀ wà. Ọgbà Yunifasiti Obafemi Awolowo to wa ni Ile-Ifẹ, ibi tó ṣe pàtàkì nínú àṣà Yorùbá. Àwọn ìlú tóṣe pàtàkì ní ìpínlẹ̀ Ọ̀sun tún ni Oke-Ila Orangun, Ila Orangun, Ede, Iwo, Ejigbo, Esa-Oke àti Ilesa.A da ipinle osun sile ni 27/08/1991,

Ọsun State
Osun State
Flag of Osun State
Flag of Osun State
Flag of Ọsun State
Flag
Nickname(s): 
Location of Ọsun State in Nigeria
Location of Ọsun State in Nigeria
Country Nigeria
Date created27 August 1991
CapitalOsogbo
Government
 • GovernorGboyega Oyetola (APC)
 • Deputy GovernorBenedict Gboyega Alabi
 • LegislatureOsun State House of Assembly
Area
 • Total9,251 km2 (3,572 sq mi)
Area rank28th of 36
Population
 (1991 census)
 • Total2,203,016
 • Estimate 
(2005)
4,137,627
 • Rank17th of 36
 • Density240/km2 (620/sq mi)
GDP (PPP)
 • Year2007
 • Total$7.28 billion[1]
 • Per capita$2,076[1]
Time zoneUTC+01 (WAT)
ISO 3166 codeNG-OS
Websitehttps://www.osunstate.gov.ng

ItanÀtúnṣe

 
Osun river in Osogbo, Osun state

Ibi tí a ń lè ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lo nii ni wọ́n da sileẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù Kẹ́́́́ ọdún 1999. Wọ́ ṣe àfàyọ ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun láti ara Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ wọ́n fún Ìpínlẹ̀ náà ní orúkọ rẹ̀ látara omi Odò Ọ̀ṣun ìyẹn omi tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òrìṣà ilẹ̀ [Yorùbá]].

ruba goddess of the same name.[4]

The former Governor Olagunsoye Oyinlola launched and laid the foundation for the groundbreaking of Osun State University with six campuses (Osogbo, Okuku, Ikire, Ejigbo, Ifetedo, and Ipetu-Ijesha) strategically located across the state. Important cultural events in the state include the Ori Oke and Egungun festival in Iragbiji,[5] Olojo in Ife and the Osun Osogbo festival.


.[6]The modern State of Osun was created on August 27, 1991 from part of the old Oyo State. The state's name is derived from the River Osun, the venerated natural spring that is the manifestation of the Yoruba goddess of the same name.[7]

ItokasiÀtúnṣe

  1. 1.0 1.1 "C-GIDD (Canback Global Income Distribution Database)". Canback Dangel. Retrieved 2008-08-20. 
  2. "Supreme Court affirms Gboyega Oyetola's election as Osun Governor". Premium Times Nigeria. 2019-07-05. Retrieved 2019-09-18. 
  3. "Appeal Court say Oyetola win Osun election". BBC News Pidgin. 2019-05-09. Retrieved 2019-09-18. 
  4. "Osun-Osogbo", Wikipedia (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 2020-04-27, retrieved 2020-06-10 
  5. "Iragbiji", Wikipedia (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 2020-05-26, retrieved 2020-06-10 
  6. "Osun-Osogbo", Wikipedia (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 2020-04-27, retrieved 2020-06-10 
  7. "Osun-Osogbo", Wikipedia (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 2020-04-27, retrieved 2020-06-10