Kofi Atta Annan ( 8 April 1938 - 18 August 2018) je omo orile-ede Ghana to je diplomati to wa ni ipo gege bi Akowe Agba keje Agbajo Iparapo awon Orile-ede lati 1 January 1997 de 31 December 2006. Annan ati Agbajo Iparapo awon Orile-ede jo gba Ebun Nobel fun Alafia ni 2001.

Kofi Annan
7th Secretary-General of the United Nations
In office
January 1, 1997 – January 1, 2007
AsíwájúBoutros Boutros-Ghali
Arọ́pòBan Ki-moon
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kẹrin 1938 (1938-04-08) (ọmọ ọdún 86)
Kumasi, Gold Coast
Ọmọorílẹ̀-èdèGhanaian
(Àwọn) olólùfẹ́Titi Alakija (divorced)
Nane Maria Annan