James Mercer Langston Hughes (February 1, 1902 – May 22, 1967) je akoewi, aseiwe-aroso, akoere-oritage ati alaroko. O je eni akoko to soro nipa iseona tuntun to un je jazz poetry. Hughes gbajumo fun awon iwe re to ko nigba Harlem Renaissance. O so nigbana pe "Harlem gbajumo".

Langston Hughes
Fọ́tò Hughes látọwọ́ Carl Van Vechten ní 1936
Ọjọ́ ìbíJames Mercer Langston Hughes
(1902-02-01)Oṣù Kejì 1, 1902
Joplin, Missouri, United States
Ọjọ́ aláìsíMay 22, 1967(1967-05-22) (ọmọ ọdún 65)
New York City, New York, United States
Iṣẹ́Poet, columnist, dramatist, essayist, novelist
Ìgbà1926–64



Itokasi àtúnṣe